SEFANÁYÀ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ọjọ́ ìdájọ́ Jèhófà ti sún mọ́lé (1-18) Ọjọ́ Jèhófà ń yára bọ̀ kánkán (14) Fàdákà àti wúrà kò ní lè gba àwọn èèyàn là (18) 2 Ẹ wá Jèhófà kí ọjọ́ ìbínú rẹ̀ tó dé (1-3) Ẹ wá òdodo àti ìwà pẹ̀lẹ́ (3) “Bóyá ẹ ó rí ààbò” (3) Ìdájọ́ lórí àwọn orílẹ̀-èdè tó yí wọn ká (4-15) 3 Jerúsálẹ́mù, ìlú tí ọ̀tẹ̀ àti ìwàkiwà kún inú rẹ̀ (1-7) Ìdájọ́ àti ìpadàbọ̀sípò (8-20) Ìyípadà sí èdè mímọ́ (9) A ó gba àwọn onírẹ̀lẹ̀ àtàwọn aláìní là (12) Jèhófà máa yọ̀ nítorí Síónì (17)