ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 December ojú ìwé 2
  • Ẹ Wá Jèhófà Kí Ọjọ́ Ìbínú Rẹ̀ Tó Dé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Wá Jèhófà Kí Ọjọ́ Ìbínú Rẹ̀ Tó Dé
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Wá Jèhófà Kí Ọjọ́ Ìbínú Rẹ̀ Tó Dé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
  • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Wòlíì—Sefanáyà
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • “Ẹ Wá Jehofa, Gbogbo Ẹ̀yin Onínútútù”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 December ojú ìwé 2
Sefanáyà ń bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SEFANÁYÀ 1–HÁGÁÌ 2

Ẹ Wá Jèhófà Kí Ọjọ́ Ìbínú Rẹ̀ Tó Dé

Sef 2:​2, 3

Tá a bá fẹ́ kí Jèhófà pa wá mọ́ ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀, ó kọjá pé ká kàn ya ara wa sí mímọ́ fún un, a tún gbọ́dọ̀ máa tẹ̀ lé àwọn ìtọ́ni tí Sefanáyà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

  • Wá Jèhófà: Ní àjọṣe tó dára pẹ̀lú Jèhófà, kó o sì máa tẹ̀ lé ìtọ́ni tí ètò rẹ̀ ń fún wa

  • Wá òdodo: Máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà

  • Wá ọkàn tútù: Máa fi ìrẹ̀lẹ̀ ṣe ìfẹ́ Jèhófà kó o sì gba ìbáwí rẹ̀

Báwo ni mo ṣe lè túbọ̀ máa wá Jèhófà, òdodo àti ọkàn tútù?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́