TÍTÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ìkíni (1-4) Kí Títù yan àwọn alàgbà ní Kírétè (5-9) Bá àwọn ọlọ̀tẹ̀ wí (10-16) 2 Ẹ̀kọ́ tó ṣàǹfààní fún tọmọdé tàgbà (1-15) Kọ àìṣèfẹ́ Ọlọ́run sílẹ̀ (12) Ìtara fún iṣẹ́ rere (14) 3 Ìtẹríba tí ó tọ́ (1-3) Múra sílẹ̀ fún iṣẹ́ rere (4-8) Yẹra fún fífa ọ̀rọ̀ tí kò mọ́gbọ́n dání àti ẹ̀ya ìsìn (9-11) Ìkíni àti ohun tó sọ fún Títù pé kí ó ṣe (12-15)