1 JÒHÁNÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Ó fi Jésù ṣe ẹbọ ìpẹ̀tù (1, 2)
Ká máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ (3-11)
Ìdí tó fi kọ̀wé sí wọn (12-14)
Ẹ má ṣe nífẹ̀ẹ́ ayé (15-17)
Ìkìlọ̀ nípa aṣòdì sí Kristi (18-29)
3
Ọmọ Ọlọ́run ni wá (1-3)
Àwọn ọmọ Ọlọ́run yàtọ̀ sí àwọn ọmọ Èṣù (4-12)
Ẹ nífẹ̀ẹ́ ara yín (13-18)
Ọlọ́run ju ọkàn wa lọ (19-24)
4
5
Ẹni tó bá gba Jésù gbọ́ ti ṣẹ́gun ayé (1-12)
Ohun tó dá wa lójú nípa agbára tí àdúrà ní (13-17)
Ẹ máa ṣọ́ra nínú ayé tó burú (18-21)