ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • nwt ojú ìwé 1610
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìgbàgbọ́ Ń sún Wa Ṣiṣẹ́!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Tẹsalóníkà
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Róòmù
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Jòhánù
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àwọn Míì
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

JÉMÍÌSÌ

OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ

  • 1

    • Ìkíni (1)

    • Ìfaradà ń jẹ́ ká láyọ̀ (2-15)

      • A máa ń dán ìgbàgbọ́ wò ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó (3)

      • Ẹ máa fi ìgbàgbọ́ béèrè (5-8)

      • Ìfẹ́ ọkàn máa ń yọrí sí ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú (14, 15)

    • Gbogbo ẹ̀bùn rere wá láti òkè (16-18)

    • Olùgbọ́ àti olùṣe ọ̀rọ̀ náà (19-25)

      • Ẹni tó ń wo ara rẹ̀ nínú dígí (23, 24)

    • Ìjọsìn tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin (26, 27)

  • 2

    • Ojúsàájú jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ (1-13)

      • Ìfẹ́ ni ọba òfin (8)

    • Ìgbàgbọ́ láìsí àwọn iṣẹ́ jẹ́ òkú (14-26)

      • Àwọn ẹ̀mí èṣù gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n (19)

      • A pe Ábúráhámù ní ọ̀rẹ́ Jèhófà (23)

  • 3

    • Bí a ṣe lè kápá ahọ́n (1-12)

      • Kí ọ̀pọ̀ má ṣe di olùkọ́ (1)

    • Ọgbọ́n tó wá láti òkè (13-18)

  • 4

    • Ẹ má ṣe jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé (1-12)

      • Ẹ dojú ìjà kọ Èṣù (7)

      • Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run (8)

    • Ìkìlọ̀ pé ká má ṣe gbéra ga (13-17)

      • “Tí Jèhófà bá fẹ́” (15)

  • 5

    • Ìkìlọ̀ fún àwọn ọlọ́rọ̀ (1-6)

    • Ọlọ́run ń bù kún àwọn tó ní sùúrù àti ìfaradà (7-11)

    • Ẹ jẹ́ kí “bẹ́ẹ̀ ni” yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni (12)

    • Àdúrà ìgbàgbọ́ lágbára (13-18)

    • Ran ẹlẹ́ṣẹ̀ lọ́wọ́ kó lè yí pa dà (19, 20)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́