2 TẸSALÓNÍKÀ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ìkíni (1, 2) Ìgbàgbọ́ àwọn ará Tẹsalóníkà ń lágbára sí i (3-5) Ẹ̀san lórí àwọn aláìgbọràn (6-10) Àdúrà fún ìjọ (11, 12) 2 Ọkùnrin arúfin (1-12) Ó gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n dúró gbọn-in (13-17) 3 Ẹ máa gbàdúrà (1-5) Ìkìlọ̀ nítorí àwọn tó ń ṣe ségesège (6-15) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (16-18)