1 TẸSALÓNÍKÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ní Tẹsalóníkà (1-12)
Àwọn ará Tẹsalóníkà gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (13-16)
Àárò àwọn ará Tẹsalóníkà ń sọ Pọ́ọ̀lù (17-20)
3
Ojú Pọ́ọ̀lù wà lọ́nà bó ṣe ń dúró ní Áténì (1-5)
Ìròyìn tó ń tuni nínú tí Tímótì mú wá (6-10)
Àdúrà fún àwọn ará Tẹsalóníkà (11-13)
4
Ìkìlọ̀ lórí ìṣekúṣe (1-8)
Ẹ túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara yín (9-12)
Àwọn tó kú nínú Kristi ló máa kọ́kọ́ dìde (13-18)
5