RÓÒMÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìkíni (1-7)
Ó wu Pọ́ọ̀lù láti lọ sí Róòmù (8-15)
Ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè (16, 17)
Àwọn èèyàn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run kò ní àwíjàre (18-32)
2
3
“Kí Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́” (1-8)
Àwọn Júù àti àwọn Gíríìkì wà lábẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ (9-20)
Òdodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (21-31)
4
5
6
Ìgbé ayé ọ̀tun nípasẹ̀ batisí sínú Kristi (1-11)
Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ jọba nínú ara yín (12-14)
Láti ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ sí ẹrú Ọlọ́run (15-23)
7
8
Ìyè àti òmìnira nípasẹ̀ ẹ̀mí (1-11)
Ẹ̀mí ìsọdọmọ ń jẹ́rìí (12-17)
Ìṣẹ̀dá ń dúró de òmìnira àwọn ọmọ Ọlọ́run (18-25)
‘Ẹ̀mí ń bá wa bẹ̀bẹ̀’ (26, 27)
Ọlọ́run yàn wá ṣáájú (28-30)
Ìfẹ́ Ọlọ́run mú kí a di aṣẹ́gun (31-39)
9
Pọ́ọ̀lù kẹ́dùn nítorí Ísírẹ́lì tara (1-5)
Ọmọ Ábúráhámù tòótọ́ (6-13)
Ohun tí Ọlọ́run bá yàn, kò sẹ́ni tó lè yí i pa dà (14-26)
Àṣẹ́kù nìkan la ó gbà là (27-29)
Ísírẹ́lì kọsẹ̀ (30-33)
10
11
Ọlọ́run ò kọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ pátápátá (1-16)
Àpèjúwe igi ólífì (17-32)
Ọgbọ́n Ọlọ́run mà jinlẹ̀ o (33-36)
12
Ẹ fi ara yín fún Ọlọ́run ní ẹbọ ààyè (1, 2)
Ẹ̀bùn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, àmọ́ ara kan náà (3-8)
Ìmọ̀ràn lórí ìgbé ayé Kristẹni tòótọ́ (9-21)
13
Ìtẹríba fún àwọn aláṣẹ (1-7)
Ìfẹ́ ni àkójá Òfin (8-10)
Máa rìn bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán (11-14)
14
Má ṣe dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́ (1-12)
Má ṣe mú ẹlòmíì kọsẹ̀ (13-18)
Mú kí àlàáfíà àti ìṣọ̀kan wà (19-23)
15
Ẹ tẹ́wọ́ gba ara yín bí Kristi ti ṣe (1-13)
Pọ́ọ̀lù, ìránṣẹ́ àwọn orílẹ̀-èdè (14-21)
Àwọn ibi tí Pọ́ọ̀lù fẹ́ rìnrìn àjò lọ (22-33)
16
Pọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ nípa Fébè tó jẹ́ òjíṣẹ́ (1, 2)
Wọ́n ń kí àwọn Kristẹni tó wà ní Róòmù (3-16)
Ìkìlọ̀ pé kí wọ́n yẹra fún ìyapa (17-20)
Àwọn tó ń bá Pọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́ kí àwọn ará (21-24)
A ti wá mọ àṣírí mímọ́ (25-27)