GÁLÁTÍÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìkíni (1-5)
Kò sí ìhìn rere míì (6-9)
Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ìhìn rere tí Pọ́ọ̀lù ń wàásù ti wá (10-12)
Bí Pọ́ọ̀lù ṣe yí pa dà àti àwọn ohun tó kọ́kọ́ ṣe (13-24)
2
Pọ́ọ̀lù lọ bá àwọn àpọ́sítélì ní Jerúsálẹ́mù (1-10)
Pọ́ọ̀lù bá Pétérù (Kéfà) wí (11-14)
A pè wá ní olódodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (15-21)
3
Àwọn iṣẹ́ Òfin àti ìgbàgbọ́ (1-14)
Ìlérí Ọlọ́run fún Ábúráhámù kì í ṣe nípasẹ̀ Òfin (15-18)
Ibi tí Òfin ti wá àti ohun tó wà fún (19-25)
Àwọn ọmọ Ọlọ́run nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (26-29)
4
Ẹ kì í ṣe ẹrú mọ́, ọmọ ni yín (1-7)
Ọ̀rọ̀ àwọn ará Gálátíà jẹ Pọ́ọ̀lù lógún (8-20)
Hágárì àti Sérà: májẹ̀mú méjì (21-31)
5
6