JÚÙDÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ Ìkíni (1, 2) Ìdájọ́ àwọn olùkọ́ èké dájú (3-16) Máíkẹ́lì bá Èṣù fa ọ̀rọ̀ (9) Àsọtẹ́lẹ̀ Énọ́kù (14, 15) Ẹ dúró nínú ìfẹ́ Ọlọ́run (17-23) Kí ògo jẹ́ ti Ọlọ́run (24, 25)