Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 8, 2001
Bí A Ṣe Lè Fòpin sí Ìwà Ìkórìíra
Ojoojúmọ́ ni ìkórìíra ń fa rògbòdìyàn àti ìjà oníwà ipá. Ibo ni ìkórìíra ti ṣẹ̀ wá gan-an? Ṣé àá lè fòpin sí i báyìí?
8 Bí a Ṣe Lè Fòpin Sí Ìwà Ìkórìíra
17 Ibi Gbogbo Ni Wọ́n Ti Ń Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́
20 Iṣẹ́ Ribiribi Làwọn Olùyọ̀ǹda Ara Ẹni Ń Ṣe
24 Iṣẹ́ Ìyọ̀ǹda Ara Ẹni Tó Ní Àǹfààní Wíwà Pẹ́ Títí
27 Mo Ń Fara Da Ìbànújẹ́ Ńláǹlà Kan
32 Àwọn Ọ̀dọ́langba Nìkan Kọ́ Ló Wà Fún
Láti ọ̀pọ̀ ọ̀rúndún sẹ́yìn ni irú ẹni tí aṣòdì sí Kristi jẹ́ gan-an ti ń fa awuyewuye. Kí ni ẹ̀rí fi hàn?
Báwo Ni Àdúrà Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́? 14
Kà nípa agbára tó ju agbára lọ tó wà nínú bíbá Ọlọ́run sọ̀rọ̀.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fọ́tò AP/John Gillis