Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March 8, 2002
Kí La Lè Ṣe Láìsí—Àwọn Olùkọ́?
Àfàìmọ̀ kí iye àwọn tó ń ṣiṣẹ́ olùkọ́ má pọ̀ ju iye àwọn tó ń ṣe oríṣi iṣẹ́ mìíràn lọ lágbàáyé. Ọpẹ́lọpẹ́ wọn lára gbogbo wa. Àmọ́, kí ló ń náni láti ṣiṣẹ́ olùkọ́? Àwọn ewu àti ìdùnnú wo ló wà nídìí iṣẹ́ náà?
3 Àwọn Olùkọ́—Èé Ṣe Tá A Fi Nílò Wọn?
5 Kí Ló Ń Mú Káwọn Èèyàn Máa Ṣe Iṣẹ́ Olùkọ́?
7 Iṣẹ́ Olùkọ́—Ohun Tó Ń Náni Àtàwọn Ewu Tó Wà Ńbẹ̀
12 Iṣẹ́ Olùkọ́—Iṣẹ́ Tó Ń Tẹni Lọ́rùn Tó sì Ń Fúnni Láyọ̀
17 Àwọn Ohun Tó Ń Fa Ewu Lẹ́nu Iṣẹ́
18 Mímú Kí Ibi Iṣẹ́ Rẹ Jẹ́ Aláìléwu
20 Kí Nìdí Tí Àwọn Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Abilà Fi Ń Nílà Lára?
30 Ṣé Lóòótọ́ ni Èṣù—Ẹni Ibi Náà Wà?
31 Oyin—Ohun Aládùn Tó Ń Wo Ọgbẹ́ Sàn
Àǹfààní Wà Nínú Kẹ̀kẹ́ Gígùn 24
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ àwọn èèyàn ló ń gun kẹ̀kẹ́ lójoojúmọ́. Àwọn kan ń gùn ún lọ síbi iṣẹ́, àwọn mìíràn sì ń fi ṣe fàájì. Irú kẹ̀kẹ́ wo ló máa dára fún ọ?
Ṣé ohun tó burú ni kí ẹ̀rí ọkàn máa dá èèyàn lẹ́bi?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 3]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: UNITED NATIONS/RAY WITLIN