Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 8, 2002
Àwọn Ìdílé Olóbìí Kan Lè Ṣàṣeyọrí
Àwọn ìdílé olóbìí kan ti wá di ohun tó wọ́pọ̀ gan-an ní ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè báyìí o. Báwo la ṣe lè borí àwọn ìṣòro tó wé mọ́ ọn?
3 Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ Túbọ̀ Ń Pọ̀ Sí I
6 Ìṣòro Tí Àwọn Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ Ń Kojú Kò Níye
10 Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ, àmọ́ Tí Kò Dá Wà
13 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
19 “Gbẹgẹdẹ Lè Gbiná Lọ́jọ́ Iwájú O”
21 Àwọn Ohun Ìjà Ayọ́kẹ́lẹ́ṣọṣẹ́—Ṣé ó Dájú Pé Àwọn Ẹni Ibi Lè Lò ó?
32 Àṣé Ó Ṣeé Ṣe Kéèyàn ní Ìdílé Aláyọ̀!
Ǹjẹ́ Ẹ̀kọ́ Ìwalẹ̀pìtàn Pọn Dandan Ká Tó Lè Ní Ìgbàgbọ́? 14
Ṣé ẹ̀kọ́ ìwalẹ̀pìtàn ló yẹ kó ṣẹ̀ṣẹ̀ fi dá wa lójú pé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni Bíbélì jẹ́?
Kí Ló Dé Tí Ọ̀kan Nínú Àwọn Òbí Mi Kò Fi Nífẹ̀ẹ́ Mi Mọ́? 16
Ṣàṣà ni ohun tó lè dun ọmọ kan wọra tó pé kí ọ̀kan nínú àwọn òbí rẹ̀ pa á tì. Báwo ni ọ̀dọ́ kan ṣe lè ṣàṣeyọrí nínú ìgbésí ayé kódà ká tiẹ̀ ní òbí kan pa á tì?