Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 8, 2003
Àwọn Ìṣòro Wo Ló Wà Nídìí Iṣẹ́ Àgbẹ̀?
Ní ọ̀pọ̀ ibi lórí ilẹ̀ ayé, ipò ọrọ̀ ajé tí kò fara rọ fún àwọn àgbẹ̀ ń kó ìdààmú kíkọyọyọ bá wọn. Kí ló ń fa ìṣòro tó bá iṣẹ́ àgbẹ̀, báwo la sì ṣe lè yanjú rẹ̀?
5 Kí Ló Ń fa Ìṣòro Tó Ń kojú Àwọn Àgbẹ̀?
9 Ìṣòro Tó Ń Kojú Àwọn Àgbẹ̀ Yóò Dópin
12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
30 Wíwo Ayé
32 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìgbéyàwó Rẹ Jẹ́ Aláyọ̀
Ọ̀nà Mẹ́fà Tí O Lè Gbà Dáàbò Bo Ìlera Rẹ 13
Ọ̀pọ̀ àìsàn la lè dènà nípa títẹ̀ lé àwọn àbá rírọrùn wọ̀nyí.
Kí nìdí tí ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́ fi fẹ́ràn láti máa fín ara? Àwọn ohun wo ló yẹ ká ronú lé lórí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Mark Segal/Index Stock Photography