Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 8, 2001
Kí Ló Fa Ìṣòro—Àwọn Ìlú Ńlá?
Ńṣe làwọn èèyàn ń rọ́ wìtìwìtì lọ sáwọn ìlú ńlá. Àmọ́, wàhálà àtibójútó àwọn èèyàn yìí ti kó ọ̀pọ̀ ìlú ńlá sínú ìyọnu.
4 Kí Ló Fa Ìṣòro—Àwọn Ìlú ńlá?
8 Báwo Lọjọ́ Iwájú Àwọn Ìlú Ńlá Ṣe Máa Rí O?
11 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
15 Ọ̀nà Tí Wọ́n Ń Gbà Jagun Lóde Òní
17 Ohun Ìjà Kéékèèké, Ìṣòro Ńláńlá
21 Ìrètí Wo Ló Ń bẹ Pé A Óò Kápá Ohun Ìjà?
29 Wíwo Ayé
32 Àràádọ́ta Ọ̀kẹ́ Yóò Lọ Síbẹ̀—Ṣé Ìwọ Náà Á Lọ?
Ṣé Ìsọfúnni Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Àlá Jẹ́?
Wọ́n Lè Jí Ohun Ìdánimọ̀ Rẹ Lọ 26
Ṣọ́ra fún ìwà ọ̀daràn kan tó ti gbalé gbòde báyìí—jíjí ohun ìdánimọ̀! Báwo lo ṣe lè dáàbò bo ara rẹ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀?