Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 8, 2004
Béèyàn Ṣe Lè Lọ́rẹ̀ẹ́ Àtàtà
Kò sóhun tó burú nínú pé kéèyàn fẹ́ láti lọ́rẹ̀ẹ́. Àmọ́, báwo lèèyàn ṣe lè lọ́rẹ̀ẹ́ àtàtà?
8 Àwọn Ọ̀rẹ́ Rere Àtọ̀rẹ́ Búburú
21 “Gbogbo Èèyàn Ló Yẹ Kó Kàwé Yìí O”
22 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
23 Aráyé Nílò Oògùn Éèdì Báyìíbáyìí!
25 Akitiyan Tí Wọ́n Ti Ṣe Láti Ṣẹ́gun Àrùn Éèdì
30 Ìgbà Wo Làrùn Éèdì Ò Ní Sí Mọ́?
32 Atọ́ka Ìdìpọ̀ Karùndínláàádọ́rùn-ún Ti jí!
Béèyàn Ṣe Lè Sá fún Ewu Tó Wà Nínú Lílo Íńtánẹ́ẹ̀tì 16
Bíbélì lè ràn wá lọ́wọ́ láti mọ bá a ṣe lè máa fọgbọ́n lo Íńtánẹ́ẹ̀tì.
Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Fún Ìyá Kan Lẹ́tọ̀ọ́ 20
Ilé ẹjọ́ gíga kan kọ ìyà fún màmá kan àtàwọn ọmọ rẹ̀ tí wọ́n fẹ̀tọ́ wọn dù.