Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October–December 2009
Kí Ló Ń Fa Ẹ̀tanú àti Àìbánilò-Lọ́gbọọgba?—Kí Lo Lè Ṣe Nípa Rẹ̀?
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ń fojú winá ìṣòro àìbánilò-lọ́gbọọgba. Kí ló ń fa ìwà kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́ yìí? Ǹjẹ́ ohun kan tiẹ̀ wà tá a lè ṣe nípa rẹ̀?
3 Àìkanisí
4 Ohun Tó Ń Fa Ẹ̀tanú àti Àìbánilò-Lọ́gbọọgba
11 Àwọn Ìṣòro Wo Ló Ń Bá Àwọn Ọ̀dọ́ Fínra?
15 Bí Àwọn Ọ̀dọ́ Ṣe Lè Rí Ìrànlọ́wọ́
18 Mo Di Ọwọ́ Ọ̀tún Ọlọ́run Mú Ṣinṣin
30 Àwọn Òbí Tó Fọwọ́ Sowọ́ Pọ̀ Tí Wọ́n sì Mọṣẹ́ Wọn Níṣẹ́
32 ‘Àpótí Tí Jèhófà Nìkan Lè Ṣí’
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Fara Dà Á bí Dádì Tàbí Mọ́mì Bá Kú? 22
Ikú òbí jẹ́ ọ̀kan lára ohun tó máa ń dunni wọra gan-an. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, wàá rí ọ̀nà tó o lè gbà fara da ọ̀pọ̀ ìbànújẹ́ téèyàn máa ń ní lẹ́yìn tí dádì tàbí mọ́mì bá kú.