Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July–September 2010
Bó o Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Sìgá Mímu
Tó o bá ń mu sìgá, ṣé ó wù ẹ́ kó o jáwọ́ ńbẹ̀? Kà nípa bó o ṣe lè borí àṣà tó ń di bárakú, tó ń gbọ́nni lówó lọ, tó sì léwu púpọ̀ yìí.
10 Ojú Ìwòye Bíbélì Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná?
12 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé Ṣé Ìbálòpọ̀ Máa Jẹ́ Ká Túbọ̀ Fẹ́ràn Ara Wa?
15 Jẹ́ Kí Àwọ̀ Ara Rẹ Tẹ́ Ọ Lọ́rùn
16 Ohun Tó Mú Kí N Fi Iṣẹ́ Olówó Gọbọi Sílẹ̀
19 Ojú Ìwòye Bíbélì Kí Ló Máa Ń Mú Ká Hùwà Rere Tàbí Búburú?
21 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Tọ́jú Ara Mi?
24 Ojú Ìwòye Bíbélì Ṣó Yẹ Kó O Máa San Owó Nítorí Àwọn Ààtò Ìsìn?
26 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Níyì Lójú Ara Mi?
29 Ohun Téèyàn Lè Ṣe Tó Bá Ń Kólòlò