Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April–June 2009
Ṣé Ọ̀gá Ẹ Ni Owó àbí Ẹrú Ẹ?
Ọ̀pọ̀ àǹfààní ló wà nínú kéèyàn lówó. Kí ló wá fà á tí ìṣòro owó fi ń yọ ọ̀pọ̀ èèyàn lẹ́nu? Àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé bó o ṣe lè lo owó lọ́nà tó mọ́gbọ́n dání.
26 O Lè Túbọ̀ Máa Rántí Nǹkan!
30 Wíwo Ayé
Ṣó Dáa Kí Wọ́n Máa Fi Iná Sun Òkú Èèyàn? 12
Ṣó burú kí wọ́n máa finá sún òkú èèyàn?