ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g21 No. 3 ojú ìwé 16
  • Ṣé Ẹlẹ́dàá Wà Lóòótọ́?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ẹlẹ́dàá Wà Lóòótọ́?
  • Jí!—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ní Ìgbàgbọ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Nínú Ẹlẹ́dàá
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Ṣé Ayé àti Ọ̀run Ní Ìbẹ̀rẹ̀?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Ẹlẹ́dàá Wà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
Àwọn Míì
Jí!—2021
g21 No. 3 ojú ìwé 16
Ọ̀dọ́kùnrin kan wà ní yàrá ìkàwé, ó ń ka ìwé náà “Was Life Created?” lórí ẹ̀rọ ìgbàlódé.

Ṣé Ẹlẹ́dàá Wà Lóòótọ́?

Ìwé yìí sọ̀rọ̀ nípa àwọn ẹ̀rí pàtàkì tó fi hàn gbangba pé ẹnì kan ló dá ayé àtàwọn ohun tó wà lójú ọ̀run. A rọ̀ ẹ́ pé kó o ṣàyẹ̀wò àwọn ẹ̀rí náà fúnra ẹ, kó o lè mọ̀ bóyá Ẹlẹ́dàá wà lóòótọ́ àbí kò sí. Gbìyànjú kó o wo àwọn fídíò tó wà nísàlẹ̀ yìí kó o sì ka àwọn ìwé tó wà níbẹ̀, ó dájú pé ó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ púpọ̀. Wá àkòrí fídíò àtàwọn ìwé náà lórí jw.org:

Kí ló mú kí ọ̀pọ̀ lára àwọn tó kàwé dáadáa gbà gbọ́ pé Ẹlẹ́dàá wà lóòótọ́?

Wo àwọn fídíò ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tó wà ní abala tá a pè ní “Èrò Àwọn Èèyàn Nípa Ìṣẹ̀dá.”

Ṣé òótọ́ lohun táwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ ẹfolúṣọ̀n ń kọ́ni?

Ka ìwé náà Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ẹ̀kọ́ 06, àkòrí ẹ̀ ni “Ṣé Ayé àti Ọ̀run Ní Ìbẹ̀rẹ̀?”

Ṣó bọ́gbọ́n mu kéèyàn gbà pé Ẹlẹ́dàá wà lóòótọ́?

Wo fídíò náà Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ​—Ọlọ́run Wà Lóòótọ́.

Ṣó bọ́gbọ́n mu kéèyàn gba ohun tí Bíbélì sọ gbọ́?

Ka ìwé náà Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ẹ̀kọ́ 03, àkòrí ẹ̀ ni “Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Gbára Lé Bíbélì?”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́