ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g22 No. 1 ojú ìwé 16
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Jí!—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2022
  • Ayé Dojú Rú—Kí Lọ̀nà Àbáyọ?
    Jí!—2022
  • Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín
    Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé
  • “Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Àwọn Míì
Jí!—2022
g22 No. 1 ojú ìwé 16

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ayé yìí ti dojú rú. Bó pẹ́ bó yá, àjálù àtàwọn ìṣòro míì táwọn èèyàn fọwọ́ ara wọn fà lè mú kí nǹkan nira fún wa lẹ́nì kọ̀ọ̀kan. Kí ló lè ran ìwọ àti ìdílé ẹ lọ́wọ́ kí ọkàn yín lè balẹ̀ bẹ́ ẹ tiẹ̀ ń kojú àwọn ìṣòro tó wà láyé yìí?

1 | Tọ́jú Ara Rẹ

Oríṣiríṣi oúnjẹ aṣaralóore wà lórí tábìlì.

2 | Ṣe Ohun Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Àtijẹ Àtimu Nira Fún Ẹ

Káfíńtà ń kan ìṣó mọ́ igi.

3 | Jẹ́ Kí Àjọṣe Ìwọ àti Tẹbítọ̀rẹ́ Dáa Sí I

Inú tọkọtaya àgbàlagbà kan ń dùn bí wọ́n ṣe dì mọ́ra wọn.

4 | Gbà Pé Ọ̀la Ń Bọ̀ Wá Dáa

Wọ́n ṣí Bíbélì kan sílẹ̀ sórí tábìlì.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́