ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g22 No. 1 ojú ìwé 3
  • Ayé Dojú Rú—Kí Lọ̀nà Àbáyọ?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ayé Dojú Rú—Kí Lọ̀nà Àbáyọ?
  • Jí!—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2022
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2022
  • 2 | Ṣe Ohun Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Àtijẹ Àtimu Nira Fún Ẹ
    Jí!—2022
  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀
    Jí!—2022
Àwọn Míì
Jí!—2022
g22 No. 1 ojú ìwé 3
Ọkàn obìnrin kan ò balẹ̀ bó ṣe ń wo fóònù ẹ̀. Ó rí àwòrán àwọn tínú ń bí, ibi tí àjálù ti ṣẹlẹ̀, ìyá kan tí nǹkan ti sú bó ṣe gbé ọmọ ẹ̀ mọ́ra, kòkòrò àrùn Kòrónà àti yàrá ilé ìwòsàn kan.

Ayé Dojú Rú​—Kí Lọ̀nà Àbáyọ?

Ojoojúmọ́ ni ìṣòro ń pọ̀ sí i láyé yìí, ó sì ṣeé ṣe kíyẹn mú kí nǹkan tojú sú ẹ. Bí àpẹẹrẹ, ó ṣeé ṣe kẹ́ ẹ máa dojú kọ díẹ̀ lára àwọn ìṣòro yìí ládùúgbò tó ò ń gbé.

  • ogun

  • àjàkálẹ̀ àrùn

  • ìmìtìtì ilẹ̀, omíyalé àtàwọn àjálù míì

  • ipò òṣì

  • kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà

  • ìwà ọ̀daràn

Tí nǹkan aburú bá ṣẹlẹ̀ láìrò tẹ́lẹ̀, ẹ̀rù sábà máa ń ba ọ̀pọ̀ èèyàn, nǹkan sì lè tojú sú wọn. Ohun tó ṣẹlẹ̀ náà sì lè mú káwọn kan bara jẹ́ ju bó ṣe yẹ lọ. Bẹ́ẹ̀ sì rèé, tí nǹkan aburú bá ṣẹlẹ̀ tẹ́nì kan ò tètè gbé ẹ̀rù tó ń bà á kúrò lọ́kàn tàbí tẹ́ni náà bara jẹ́ jù, kò ní lè ronú dáadáa, ìyẹn sì lè dá kún ìṣòro náà.

Ní báyìí tí nǹkan ń nira sí i láyé yìí, o gbọ́dọ̀ tètè wá nǹkan ṣe kó o lè mójú tó ìlera ẹ àti ọ̀rọ̀ nípa àtijẹ àtimu, kó o sì lè dáàbò bo àwọn mọ̀lẹ́bí, àwọn ọ̀rẹ́ ẹ àtàwọn nǹkan míì tó lè fún ẹ láyọ̀.

Bí ìṣòro bá tiẹ̀ ń pọ̀ sí i láyé yìí, kí lo lè ṣe tí nǹkan ò fi ní nira fún ẹ?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́