Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀
Bí nǹkan ṣe ń burú sí i láyé yìí, ọ̀pọ̀ èèyàn ló ń jìyà nítorí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àdáyébá tàbí àwọn àjálù táwọn èèyàn ń fọwọ́ ara wọn fà. Ka ìwé yìí kó o lè rí bó o ṣe lè máa fara dà á àtohun tó o lè ṣe láti dáàbò bo ara rẹ àtàwọn ẹlòmíì.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.