ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g23 No. 1 ojú ìwé 16
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Jí!—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2023
  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀
    Jí!—2023
  • Ọlọ́run Ṣèlérí Pé Ayé Yìí Máa Wà Títí Láé
    Jí!—2023
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Jí!—2023
g23 No. 1 ojú ìwé 16
Èéfín tó lè ba àyíká jẹ́ ń tú jáde láti ilé iṣẹ́ kan sínú afẹ́fẹ́.

Xuanyu Han/Moment via Getty Images

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ojoojúmọ́ làwọn èèyàn túbọ̀ ń sọ ayé yìí di ibi tó léwu.

Ṣé wọn ò ní ba ayé yìí jẹ́ kọjá àtúnṣe, débi tí ohun alààyè kankan ò fi ní lè gbébẹ̀ mọ́? Ka àwọn àpilẹ̀kọ yìí kó o lè mọ oríṣiríṣi ohun táwọn èèyàn ti ṣe láti ba ayé yìí jẹ́, kó o sì rí àwọn ẹ̀rí tó fi hàn pé ọ̀nà àbáyọ wà.

Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sáwọn nǹkan yìí lọ́jọ́ iwájú?

  • Omi tó mọ́

  • Òkun

  • Igbó kìjikìji

  • Afẹ́fẹ́

KẸ́KỌ̀Ọ́ SÍ I

Obìnrin kan ń mú Bíbélì jáde látinú ibi ìkówèésí.

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló nígbàgbọ́ nínú ìlérí tí Ọlọ́run ṣe pé òun máa tún ayé yìí ṣe káwọn èèyàn lè máa gbádùn ara wọn níbẹ̀ títí láé. Wo fídíò náà Báwo La Ṣe Mọ̀ Pé Òótọ́ ni Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì? lórí jw.org.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́