ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yp2 ojú ìwé 172-173
  • Àwọn Òbí Rẹ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Òbí Rẹ
  • Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Mọ Àwọn Òbí Mi?
    Jí!—2010
  • Kí Ni Kí N Ṣe Báwọn Òbí Mi Bá Ń Jà?
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
  • Kí Nìdí Tí Ọ̀rọ̀ Mi Kò Fi Yé Àwọn Òbí Mi?
    Jí!—2012
  • Ẹ̀yin Èwe Ẹ Lè Múnú Àwọn Òbí Yín Dùn Tàbí Kẹ́ Ẹ Bà Wọ́n Nínú Jẹ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
yp2 ojú ìwé 172-173

APÁ 6

Àwọn Òbí Rẹ

Àǹfààní gbáà ni ìrírí táwọn òbí ní jẹ́ fún wọn. Wọ́n ti kojú àwọn ìyípadà tó máa ń dé bá ara àti onírúurú èrò tó máa ń wá síni lọ́kàn nígbà ìbàlágà. Ó ṣe wẹ́kú nígbà náà pé àwọn gan-an ló lè tọ́ ẹ sọ́nà kó o má bàa kó síṣòro bíwọ náà ṣe ń gòkè àgbà. Àmọ́ ṣá, ó lè dà bíi pé ńṣe làwọn òbí ń dá kún ìṣòro dípò kí wọ́n yanjú ẹ̀. Bí àpẹẹrẹ, o lè máa kojú ọ̀kan lára àwọn ìṣòro wọ̀nyí:

□ Àwọn òbí mi kì í yé rí sí mi.

□ Dádì tàbí Mọ́mì ti ki àṣejù bọ ọtí mímu tàbí lílo oògùn olóró.

□ Ńṣe làwọn òbí mi máa ń jà ṣáá.

□ Àwọn òbí mi ti fira wọn sílẹ̀.

Orí 21 sí 25 nínú ìwé yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ ohun tó o lè ṣe nípa àwọn ìṣòro yìí àtàwọn ìṣòro míì.

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 172, 173]

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́