ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sn orin 69
  • Mú Mi Mọ Àwọn Ọ̀nà Rẹ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Mú Mi Mọ Àwọn Ọ̀nà Rẹ
  • Kọrin sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Mú Mi Mọ Àwọn Ọ̀nà Rẹ
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ
    Kọrin sí Jèhófà
  • Jọ̀ọ́, Gbọ́ Àdúrà Mi
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
Kọrin sí Jèhófà
sn orin 69

Orin 69

Mú Mi Mọ Àwọn Ọ̀nà Rẹ

Bíi Ti Orí Ìwé

(Sáàmù 25:4)

1. Jèhófà Ọlọ́run wa, a ti pé jọ,

Ìwọ lo fìfẹ́ pè wá síbí.

Ọ̀rọ̀ rẹ jẹ́ fìtílà fún ọ̀nà wa,

Ó ńkọ́ wa lẹ́kọ̀ọ́ àtọ̀runwá.

(ÈGBÈ)

Kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, mú kí nlóye;

Mú kétí mi gbọ́ àṣẹ ọlọ́gbọ́n.

Mú kí nmáa rìn ní ọ̀nà òtítọ́,

Mú kí òfin rẹ jẹ́ ìdùnnú mi.

2. Ọlọ́run, ọgbọ́n rẹ ju gbogbo ọgbọ́n;

Ìpinnu rẹ fọkàn wa balẹ̀.

Ọ̀rọ̀ rẹ jẹ́ ìyanu títí ayé;

Ohun tóo sọ dúró títí láé.

(ÈGBÈ)

Kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, mú kí nlóye;

Mú kétí mi gbọ́ àṣẹ ọlọ́gbọ́n.

Mú kí nmáa rìn ní ọ̀nà òtítọ́,

Mú kí òfin rẹ jẹ́ ìdùnnú mi.

(Tún wo Ẹ́kís. 33:13; Sm. 1:2; 119:27, 35, 73, 105.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́