Kọrin sí Jèhófà (sn) Kọrin sí Jèhófà Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Orin 1 Àwọn Ànímọ́ Jèhófà Orin 2 A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Rẹ Jèhófà Orin 3 “Ọlọ́run Jẹ́ Ìfẹ́” Orin 4 Bá A Ṣe Lè Ní Orúkọ Rere Lọ́dọ̀ Ọlọ́run Orin 5 Kristi, Àwòfiṣàpẹẹrẹ Wa Orin 6 Àdúrà Ìránṣẹ́ Ọlọ́run Orin 7 Ìyàsímímọ́ Kristẹni Orin 8 Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa Orin 9 Ẹ Yin Jèhófà, Ọlọ́run Wa! Orin 10 “Èmi Nìyí! Rán Mi” Orin 11 Mímú Ọkàn Jèhófà Yọ̀ Orin 12 Ọlọ́run Ṣèlérí Ìyè Àìnípẹ̀kun Orin 13 Àdúrà Ìdúpẹ́ Jèhófà Sọ Ohun Gbogbo Di Tuntun Orin 15 Ìṣẹ̀dá Ń Ṣí Ògo Jèhófà Payá Orin 16 Ẹ Sá Wá Sábẹ́ Ìjọba Ọlọ́run! Orin 17 Ẹ Tẹ̀ Síwájú Ẹ̀yin Ẹlẹ́rìí! Orin 18 Ìfẹ́ Ọlọ́run Tó Dúró Ṣinṣin Orin 19 Ọlọ́run Ṣèlérí Párádísè Orin 20 Bù Kún Ìpéjọ Wa Orin 21 Aláyọ̀ Ni Àwọn Aláàánú! Orin 22 “Jèhófà Ni Olùṣọ́ Àgùntàn Mi” Orin 23 Jèhófà, Okun Wa Orin 24 Tẹjú Mọ́ Èrè Náà! Orin 25 Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Ọmọ Ẹ̀yìn Kristi Ni Wá Orin 26 Bá Ọlọ́run Rìn! Orin 27 Dúró Sọ́dọ̀ Jèhófà! Orin 28 Orin Tuntun Orin 29 Rírìn Nínú Ìwà Títọ́ Orin 30 Jèhófà Bẹ̀rẹ̀ Ìṣàkóso Rẹ̀ Orin 31 Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ni Wá! Orin 32 Ẹ Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin! Orin 33 Ẹ Má Bẹ̀rù Wọn! Orin 34 Jíjẹ́ Kí Orúkọ Wa Máa Rò Wá Orin 35 Ọpẹ́ fún Sùúrù Ọlọ́run Orin 36 “Ohun Tí Ọlọ́rùn Ti So Pọ̀” Orin 37 Ọlọ́run Mí sí Ìwé Mímọ́ Orin 38 Ju Ẹrù Ìnira Rẹ Sọ́dọ̀ Jèhófà Orin 39 Àlàáfíà Tó Wà Láàárín Wa Orin 40 Ẹ Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́ Orin 41 Sin Jèhófà Nígbà Èwe Orin 42 “Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Tí Wọ́n Jẹ́ Aláìlera” Orin 43 Ẹ Wà Lójúfò, Ẹ Dúró Gbọn-in, Ẹ Di Alágbára Orin 44 Máa Fìdùnnú Kópa Nínú Ìkórè Náà Orin 45 Ẹ Máa Tẹ̀ Síwájú! Orin 46 Jèhófà Ni Ọba Wa! Orin 47 Polongo Ìhìn Rere Orin 48 Bíbá Jèhófà Rìn Lójoojúmọ́ Orin 49 Jèhófà Ni Ibi Ìsádi Wa Orin 50 Àpẹẹrẹ Ìfẹ́ Ọlọ́run Orin 51 A Rọ̀ Mọ́ Jèhófà Orin 52 Máa Ṣọ́ Ọkàn Rẹ Orin 53 Ṣíṣiṣẹ́ Pa Pọ̀ ní Ìṣọ̀kan Orin 54 A Ní Láti Nígbàgbọ́ Orin 55 Ìyè Àìnípẹ̀kun Nígbẹ̀yìngbẹ́yín! Orin 56 Jọ̀wọ́ Gbọ́ Àdúrà Mi Orin 57 Àṣàrò Ọkàn Mi Orin 58 Àdúrà Ìyàsímímọ́ Mi Orin 59 Ọlọ́run Ni A Ya Ara Wa sí Mímọ́ Fún! Orin 60 Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára Orin 61 Irú Ènìyàn Tó Yẹ Kí N Jẹ́ Orin 62 Ti Ta Ni Àwa Jẹ́? Orin 63 Jẹ́ Adúróṣinṣin Orin 64 Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ Orin 65 “Èyí Ni Ọ̀nà” Orin 66 Fífi Gbogbo Ọkàn Sin Jèhófà Orin 67 Máa Gbàdúrà sí Jèhófà Lójoojúmọ́ Orin 68 Àdúrà Ẹni Rírẹlẹ̀ Orin 69 Mú Mi Mọ Àwọn Ọ̀nà Rẹ Orin 70 “Máa Wádìí Dájú Àwọn Ohun Tí Ó Ṣe Pàtàkì Jù” Orin 71 Ẹ̀mí Mímọ́, Ẹ̀bùn Ọlọ́run Orin 72 Bá A Ṣe Lè Ní Ìfẹ́ Orin 73 Ká Nífẹ̀ẹ́ Ara Wa Látọkàn Wá Ìdùnnú Jèhófà Ìdí Ayọ̀ Wa Pọ̀ Orin 76 Jèhófà, Ọlọ́run Àlàáfíà Orin 77 Ẹ Máa Dárí Jini Orin 78 Ìpamọ́ra Orin 79 Agbára Inú Rere Orin 80 Ìwà Rere Orin 81 “Fún Wa Ní Ìgbàgbọ́ Sí I” Orin 82 Jẹ́ Onínú Tútù Bíi Kristi Orin 83 Ó Yẹ Ká Ní Ìkóra-Ẹni-Níjàánu Orin 84 “Mo Fẹ́ Bẹ́ẹ̀” Orin 85 Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Èrè Látọ̀dọ̀ Jèhófà Orin 86 Àwọn Obìnrin Olóòótọ́, Àwọn Arábìnrin Orin 87 A Ti Di Ọ̀kan Ṣoṣo Orin 88 Ọmọ Jẹ́ Ohun Ìní Tí Ọlọ́run Fi Síkàáwọ́ Òbí Orin 89 Jèhófà Fìfẹ́ Rọ̀ Ọ́ Pé: “Ọmọ Mi, Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n” Orin 90 Ẹwà Orí Ewú Orin 91 Baba Mi, Ọlọ́run Mi àti Ọ̀rẹ́ Mi Orin 92 “Wàásù Ọ̀rọ̀ Náà” Orin 93 “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn” Orin 94 Àwọn Ẹ̀bùn Rere Ọlọ́run Tẹ́ Wa Lọ́rùn Orin 95 “Ẹ Tọ́ Ọ Wò, Kí Ẹ sì Rí I Pé Jèhófà Jẹ́ Ẹni Rere” Orin 96 Ẹ Wá Àwọn Ẹni Yíyẹ Kàn Orin 97 Ẹ Tẹ̀ Síwájú, Ẹ̀yin Òjíṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run! Orin 98 Fífúnrúgbìn Èso Ìjọba Ọlọ́run Orin 99 Ẹ Yin Ọba Tuntun Tó Jẹ Lórí Ayé Orin 100 Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Jèhófà Ni Wá! Orin 101 Sísọ Òtítọ́ Ìjọba Ọlọ́run Di Mímọ̀ Orin 102 Dara Pọ̀ Nínú Kíkọ Orin Ìjọba Náà! Orin 103 “Láti Ilé dé Ilé” Orin 104 Ẹ Bá Mi Yin Jáà Orin 105 Àwọn Ọ̀run Ń Polongo Ògo Ọlọ́run Orin 106 Bá A Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà Orin 107 Wá sí Òkè Jèhófà Orin 108 Ẹ Yin Jèhófà Nítorí Ìjọba Rẹ̀ Orin 109 Yin Àkọ́bí Jèhófà! Orin 110 Àwọn Iṣẹ́ Àgbàyanu Ọlọ́run Orin 111 Òun Yóò Pè Orin 112 Jèhófà, Ọlọ́run Gíga Orin 113 A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Ọlọ́run Nítorí Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ Orin 114 Ìwé Ọlọ́run Jẹ́ Ìṣúra Orin 115 Bá A Ṣe Lè Ṣe Ọ̀nà Wa Ní Rere Orin 116 Ìmọ́lẹ̀ Náà Ń Mọ́lẹ̀ Sí I Orin 117 A Gbọ́dọ̀ Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Jèhófà Orin 118 Ẹ Fìdùnnú Tẹ́wọ́ Gba Ara Yín Orin 119 Ẹ Wá Gba Ìtura! Orin 120 Gbọ́, Ṣègbọràn, Kó O sì Gba Ìbùkún Orin 121 Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí Orin 122 Ẹgbẹẹgbẹ̀rún Àwa Ará Orin 123 Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Jẹ́ Ẹ̀bùn Orin 124 Gbà Wọ́n Pẹ̀lú Ẹ̀mí Aájò Àlejò Orin 125 Fífi Ìdúróṣinṣin Tẹrí Ba fún Ìṣàkóso Ọlọ́run Orin 126 Òpò Tá A Fi Ìfẹ́ Ṣe Orin 127 Ibi Tá A Ń Fi Orúkọ Rẹ Pè Orin 128 Ipò Nǹkan Ń Yí Pa Dà Ní Ayé Yìí Orin 129 Dídi Ìrètí Wa Mú Ṣinṣin Orin 130 Ìyanu Ni Ìwàláàyè Jẹ́ Orin 131 Jèhófà Ń Ṣe Ọ̀nà Àsálà Orin 132 Orin Ìṣẹ́gun Orin 133 Wá Ọlọ́run Kó O Lè Rí Ìgbàlà Orin 134 Fojú Inú Wo Ìgbà Tí Gbogbo Nǹkan Yóò Di Tuntun Orin 135 Fífara Dà Á Dópin