Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Kọrin sí Jèhófà
“Ṣe ni èmi yóò máa kọrin sí Jèhófà jálẹ̀ ìgbésí ayé mi; Èmi yóò máa kọ orin atunilára sí Ọlọ́run mi níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà.”—SÁÀMÙ 104:33
ORÚKỌ ․․․․․․․․․․․․․․․․
ÌJỌ ․․․․․․․․․․․․․․․․
© 2009
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA
ÀWA ÒǸṢÈWÉ
WATCHTOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF NEW YORK, INC.
BROOKLYN, NEW YORK, U.S.A.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2009
Ìwé yìí kì í ṣe títà. Ńṣe là ń tẹ̀ ẹ́ jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.