ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mb ẹ̀kọ́ 6
  • Ẹ̀kọ́ 6

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀kọ́ 6
  • Ẹ̀kọ́ Bíbélì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọlọ́run Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-Tìyanu
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ẹ̀kọ́ 5
    Ẹ̀kọ́ Bíbélì
  • Ẹ̀kọ́ 1
    Ẹ̀kọ́ Bíbélì
  • Ọlọrun Ha Mọ̀ Ọ́ Níti Gidi Bí?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
Àwọn Míì
Ẹ̀kọ́ Bíbélì
mb ẹ̀kọ́ 6

Ẹ̀kọ́ 6

Sáàmù 139:14

Wo ìka ọwọ́ rẹ àti ìka ẹsẹ̀ rẹ.

Fọwọ́ kan etí rẹ àti imú rẹ.

Wo ẹsẹ̀ tó o fi ń fò, tó o fi ń sáré, tó o tún fi ń yípo. Òun náà lo fi ń ṣeré káàkiri!

Wo ojú dígí, kí lo rí níbẹ̀?

Gbogbo nǹkan ni Jèhófà ṣe dáadáa!

IṢẸ́ ÒBÍ

Ka ẹsẹ Bíbélì yìí fún ọmọ rẹ:

Sáàmù 139:14

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

Ìka ọwọ́ rẹ̀ Ìka ẹsẹ̀ rẹ̀ Imú rẹ̀

Etí rẹ̀ Ẹnu rẹ̀

Fara balẹ̀ wá àwọn nǹkan yìí.

Alákàn Ológbò

Bi ọmọ rẹ pé:

Ta ló dá ìwọ àti èmi?

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 14]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 15]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 15]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 16]

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́