ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 September ojú ìwé 5
  • Ọlọ́run Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-Tìyanu

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọlọ́run Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-Tìyanu
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọlọ́run ‘Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-tìyanu’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Ọlọrun Ha Mọ̀ Ọ́ Níti Gidi Bí?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Ọ̀rọ̀ Rẹ Yé Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Kárùn-Ún Sáàmù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 September ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 135-141

Ọlọ́run Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-Tìyanu

Dáfídì ṣe àṣàrò lórí àwọn ànímọ́ rere tí Ọlọ́run ní, èyí tó hàn nínú ìṣẹ̀dá. Ọkàn rẹ̀ balẹ̀ bó ṣe ń fi ayé rẹ̀ sin Jèhófà.

Aláboyun kan àti ọkọ rẹ̀ láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì

Nígbà tí Dáfídì ronú jinlẹ̀ nípa ìṣẹ̀dá, èyí mú kó yin Jèhófà:

139:14

  • “Èmi yóò gbé ọ lárugẹ, nítorí pé lọ́nà amúnikún-fún-ẹ̀rù ni a ṣẹ̀dá mi tìyanu-tìyanu”

139:15

  • “Àwọn egungun mi kò pa mọ́ fún ọ, nígbà tí a ṣẹ̀dá mi ní ìkọ̀kọ̀, nígbà tí a hun mí ní àwọn apá ìsàlẹ̀ jù lọ ní ilẹ̀ ayé”

139:16

  • “Àní ojú rẹ rí ọlẹ̀ mi, inú ìwé rẹ sì ni gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà ní àkọsílẹ̀”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́