September Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, September 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò September 5 sí 11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 119 “Máa Rìn Nínú Òfin Jèhófà” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Tí Ọmọdé Kan Bá Sọ Pé Ká Wọlé September 12 sí 18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 120-134 “Ọ̀dọ̀ Jèhófà Ni Ìrànlọ́wọ́ Mi Ti Wá” September 19 sí 25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 135-141 Ọlọ́run Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-Tìyanu MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Nǹkan Tó Yẹ Kó O Yẹra fún Tó O Bá Ń Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì September 26 sí October 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 142-150 “Jèhófà Tóbi, Ó sì Yẹ fún Ìyìn Gidigidi” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fún Àwọn Tó Bá Nífẹ̀ẹ́ sí Ọ̀rọ̀ Wa Níṣìírí Láti Wá sí Ìpàdé