Àwọn ẹ̀kọ́ tó o lè kọ́ látinú Bíbélì
ÀWỌN Ẹ̀KỌ́
A gbọ́dọ̀ wàásù ìhìn rere Ìjọba náà 73, 76, 94, 95, 96, 97, 98
A ò lè sin Ọlọ́run, ká sì máa lépa ọrọ̀ 10, 17, 44, 59, 75, 76
Alágbára ńlá ni Jèhófà 1, 7, 18, 19, 20, 21, 22, 26, 55, 60
Àwọn ẹni burúkú ò ní sí mọ́ 5, 10, 32, 46, 102
Àwọn ọlọ̀tẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run 7, 17, 26, 27, 28, 88
Àwọn tó bá nífẹ̀ẹ́ Jèhófà ni ọ̀rẹ́ tó dáa jù 16, 33, 42, 80, 87, 100, 103
Di ọ̀rẹ́ Jèhófà 11, 30, 33, 51, 56, 59, 69, 81, 82
Ẹ̀yin ọ̀dọ́, ẹ sin Jèhófà tọkàntọkàn 37, 51, 59, 61, 72, 100
Gbọ́, ṣègbọràn kó o lè wà láàyè 3, 5, 10, 37, 39, 54, 59, 65, 72
Gbogbo èèyàn ṣeyebíye lójú Jèhófà 8, 9, 11, 21, 23, 68, 70, 74, 87, 90
Ìbínú ò dáa 4, 12, 41, 45, 49, 65, 89
Ìfẹ́ Ọlọ́run máa ṣẹ lọ́run àti láyé 25, 55, 60, 62, 63, 71, 96, 102
Ìjọba Ọlọ́run máa mú kí gbogbo èèyàn láyọ̀ 1, 48, 62, 79, 81, 83, 85, 86
Ìmọtara-ẹni-nìkan ò dáa 3, 4, 12, 27, 28, 39, 49, 88
Jẹ́ onígboyà, Jèhófà máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ 40, 47, 51, 53, 57, 61, 64, 65, 76, 88, 101
Jèhófà kì í parọ́ 3, 10, 16, 63, 68, 70, 102, 103
Jèhófà ò ní gbàgbé ohun tá a bá ṣe fún un 16, 29, 32, 48, 65, 69, 77, 100
Jèhófà máa ń dáàbò bo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ 6, 22, 40, 50, 52, 55, 64, 71, 84
Jèhófà máa ń gbọ́ àdúrà àtọkàn wa 35, 38, 50, 64, 82
Jèhófà ń dáàbò bo àwọn onírẹ̀lẹ̀ 43, 45, 65, 67, 69
Jèhófà ń darí àwọn èèyàn rẹ̀ 18, 25, 26, 27, 29, 34, 39, 44, 73, 80
Jèhófà nífẹ̀ẹ́ gbogbo èèyàn 30, 33, 48, 54, 77, 94, 97, 98, 99
Má ṣe jẹ́ kí ohun tí Jèhófà fún ẹ bọ́ mọ́ ẹ lọ́wọ́ 12, 13, 24, 35, 36, 56, 75, 95, 100
Má ṣe rẹ̀wẹ̀sì tó o bá ń jìyà 16, 47, 51, 57, 64, 75, 90, 95, 99, 101
Máa dárí ji àwọn míì bí Jèhófà ṣe ń dárí jì ẹ́ 13, 15, 31, 43, 92
Máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà nígbà gbogbo 2, 6, 67, 103
Máa mú ìlérí rẹ ṣẹ bíi Jèhófà 8, 9, 11, 23, 24, 31, 34, 35, 36, 66, 93
Owú máa ń ba àárín ọ̀rẹ́ jẹ́ 4, 14, 41
Ọ̀dọ̀ Èṣù ni ìjọsìn èké ti wá 19, 20, 22, 38, 46, 49, 52, 58
Ọlọ́run fún wa ní Bíbélì ká lè gbọ́n 56, 66, 72, 75, 81
Sá fún ohun búburú 14, 27, 49, 53, 58, 88, 89
Ṣègbọràn sí Jésù torí òun ni Ọba Ìjọba Ọlọ́run 74, 78, 79, 83, 84, 85, 91, 92, 99
Tó ò bá nífẹ̀ẹ́ arákùnrin ẹ, o ò lè nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run 4, 13, 15, 41