APÁ 4 Bíi Ti Orí Ìwé Ohun tó dá lé: Bá a ṣe lè máa ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run títí láé Ẹ̀KỌ́ 48 Fọgbọ́n Yan Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ 49 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?—Apá Kìíní 50 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?—Apá Kejì 51 Báwo La Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Tá À Ń Sọ Múnú Jèhófà Dùn? 52 Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Múra Lọ́nà Tó Bójú Mu 53 Yan Eré Ìnàjú Táá Múnú Jèhófà Dùn 54 Ta Ni “Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye”? 55 Máa Ṣètìlẹyìn fún Ìjọ 56 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kí Àlàáfíà àti Ìṣọ̀kan Wà Nínú Ìjọ 57 Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Dá Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Burú Gan-an? 58 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà 59 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Táwọn Èèyàn Bá Tiẹ̀ Ń Ta Kò Ẹ́ 60 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Sún Mọ́ Jèhófà