ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • lff apá 4
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4
  • Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 3
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 2
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 1
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Fídíò àti Ìwé Tá A Tọ́ka Sí
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì
Àwọn Míì
Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
lff apá 4

Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4

  1. 48 Fọgbọ́n Yan Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ

  2. 49 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?​—Apá Kìíní

  3. 50 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?​—Apá Kejì

  4. 51 Báwo La Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Tá À Ń Sọ Múnú Jèhófà Dùn?

  5. 52 Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Múra Lọ́nà Tó Bójú Mu

  6. 53 Yan Eré Ìnàjú Táá Múnú Jèhófà Dùn

  7. 54 Ta Ni “Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye”?

  8. 55 Máa Ṣètìlẹyìn fún Ìjọ

  9. 56 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kí Àlàáfíà àti Ìṣọ̀kan Wà Nínú Ìjọ

  10. 57 Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Dá Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Burú Gan-an?

  11. 58 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà

  12. 59 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Táwọn Èèyàn Bá Tiẹ̀ Ń Ta Kò Ẹ́

  13. 60 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Sún Mọ́ Jèhófà

48 Fọgbọ́n Yan Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ

Pinnu Láti Kọ Ẹgbẹ́ Búburú Sílẹ̀ Lákọ̀tán (6:17)

Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Ní Ibi Tí O Ò Lérò (5:06)

Ta Ni Ọ̀rẹ́ Tòótọ́? (4:14)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Àwọn Ará Kí Òpin Tó Dé” (Ilé Ìṣọ́, November 2019)

“Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Dáa?” (Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè​—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kìíní, orí 8)

Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò (4:12)

“Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, April 1, 2012)

49 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?​—Apá Kìíní

Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Máa Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aya Yín Bí Ara Yín (9:53)

Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Túbọ̀ Ṣe Ara Wọn Lọ́kan (5:44)

ṢÈWÁDÌÍ

Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀ (ìwé)

Ìfẹ́ Tòótọ́ (4:26)

“Ẹ̀yin Obìnrin, Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kẹ́ Ẹ Máa Tẹrí Ba Fún Ipò Orí?” (Ilé Ìṣọ́, May 15, 2010)

Jèhófà Ló Bá Wa Tún Ìdílé Wa Tò (5:14)

50 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?​—Apá Kejì

Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Ibi (2:58)

Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ (1:52)

“Agbára Jésù Ju Ti Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Lọ” (Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà, orí 10)

“Bí Ọlọ́run Ṣe Dáàbò Bo Jésù” (Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà, orí 32)

“Kọ́ Ọmọ Rẹ Nípa Ìbálòpọ̀” (Jí! No. 5 2016)

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Sọ Tinú Mi Fáwọn Òbí Mi? (2:19)

Ìjọsìn Ìdílé​—Àwọn Ìṣòro àti Ayọ̀ Ibẹ̀ (8:04)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ohun Mẹ́fà Tó Yẹ Ká Kọ́ Àwọn Ọmọ” (Jí! No. 2 2019)

“Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí A Ṣe Lè Tọ́jú Àwọn Òbí Wa Tó Ti Dàgbà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

Jèhófà Ló Bá Wa Tọ́ Àwọn Ọmọ Wa (5:58)

“Kí Làwọn Bàbá Lè Ṣe Tí Àjọṣe Wọn Pẹ̀lú Ọmọkùnrin Wọn Kò Fi Ní Bà Jẹ́?” (Ilé Ìṣọ́, November 1, 2011)

51 Báwo La Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Tá À Ń Sọ Múnú Jèhófà Dùn?

Máa Sọ “Ọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró” Fáwọn Míì (4:07)

Ìfẹ́ àti Ọ̀wọ̀ Ń Mú Kí Ìdílé Wà Níṣọ̀kan (3:08)

ṢÈWÁDÌÍ

Ẹ Sapá Láti Ní Ahọ́n Ọlọ́gbọ́n (8:04)

“Ṣé Ó Fi Bẹ́ẹ̀ Burú Kéèyàn Máa Ṣépè?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Òfófó? (2:36)

“Mo Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ronú Gidigidi Nípa Ibi Tí Mo Ń Bọ́rọ̀ Ayé Mi Lọ” (Ilé Ìṣọ́, August 1, 2013)

52 Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Múra Lọ́nà Tó Bójú Mu

“Ẹ Máa Ṣe Ohun Gbogbo fún Ògo Ọlọ́run” (10:18)

ṢÈWÁDÌÍ

“Báwo Ni Ìmúra Mi Ṣe Rí?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Fínfín Àmì sí Ara?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ǹjẹ́ Ìmúra Rẹ Ń Fògo fún Ọlọ́run?” (Ilé Ìṣọ́, September 2016)

“Ìmúra àti Ìwọṣọ Ni Kò Jẹ́ Kí N Tètè Rí Òtítọ́” (Jí!, March 8, 2004)

53 Yan Eré Ìnàjú Táá Múnú Jèhófà Dùn

Eré Ìnàjú Wo Ló Yẹ Kí N Yàn Láàyò? (4:39)

Báwo Lo Ṣe Ń Lo Àkókò Rẹ? (2:45)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ṣé Ó Láwọn Fíìmù, Ìwé Tàbí Orin Tẹ́yin Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ò Gbọ́dọ̀ Gbádùn?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ṣé Eré Ìtura Tó O Yàn Máa Ṣe Ẹ́ Láǹfààní?” (Ilé Ìṣọ́, October 15, 2011)

“Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, February 1, 2010)

Yẹra fún Eré Ìnàjú Tó Ní Ìtàn Nípa Àwọn Ẹlẹ́mìí Òkùnkùn (2:02)

54 Ta Ni “Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye?

Jèhófà Mú Kí Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò (6:18)

Iṣẹ́ Ìwàásù La Kà Sí Pàtàkì Jù (1:24)

ṢÈWÁDÌÍ

“Kí Là Ń Pè Ní Ìgbìmọ̀ Olùdarí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

A Máa Ń Rí I Pé Ohun Tó Wà Nínú Àwọn Ìtẹ̀jáde Wa Péye (17:18)

Àǹfààní Ńlá Ni Kéèyàn Sìnrú fún Jèhófà (7:04)

Jèhófà Ń Kọ́ Àwa Èèyàn Rẹ̀ (9:39)

55 Máa Ṣètìlẹyìn fún Ìjọ

‘Wọ́n Mú Ẹ̀bùn Wá fún Jèhófà’ (4:47)

Bá A Ṣe Lè Máa Bójú Tó Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa (3:31)

Ẹ̀yin Arákùnrin​—Ẹ Wá Bẹ́ Ẹ Ṣe Máa Ṣe Púpọ̀ Sí I Nínú Iṣẹ́ Ọlọ́run (5:19)

ṢÈWÁDÌÍ

“Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìdá Mẹ́wàá?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Mọyì Ipò Orí Tí Jèhófà Ṣètò Nínú Ìjọ” (Ilé Ìṣọ́, February 2021)

Bí A Ṣe Ń Pín Àwọn Ìwé Tó Ṣàlàyé Bíbélì Lórílẹ̀-Èdè Congo (4:25)

“Ibo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ń Rówó Tí Wọ́n Ń Ná?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

56 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kí Àlàáfíà àti Ìṣọ̀kan Wà Nínú Ìjọ

Máa Wá Àlàáfíà Kó O Lè Rí Ìbùkún (6:01)

Máa Sunwọ̀n Sí I Lójoojúmọ́! (5:10)

ṢÈWÁDÌÍ

Yọ Igi ìrólé (6:56)

“Títọrọ Àforíjì, Ọ̀nà Tó Gbéṣẹ́ Jù Lọ Láti Wá Àlàáfíà” (Ilé Ìṣọ́, November 1, 2002)

Má Ṣe Máa Fi Ìrísí Dáni Lẹ́jọ́ (5:06)

“Ẹ Máa Fìfẹ́ Yanjú Aáwọ̀” (Ilé Ìṣọ́, May 2016)

57 Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Dá Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Burú Gan-an?

“Àwọn Tí Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ló Máa Ń Bá Wí” (3:01)

ṢÈWÁDÌÍ

Aláàánú Ni Jèhófà (5:02)

“Bá A Ṣe Lè Ṣàánú Ẹni Tó Dẹ́ṣẹ̀, Ká sì Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Ẹ̀” (Ilé Ìṣọ́, August 2024)

“Báwọn Alàgbà Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Fáwọn Tí Wọ́n Mú Kúrò Nínú Ìjọ” (Ilé Ìṣọ́, August 2024

“Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, April 1, 2012)

58 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà

Ẹ Jáde Kúrò Nínú Bábílónì Ńlá! (5:06)

ṢÈWÁDÌÍ

“Máa Rí Àrídájú Ọ̀rọ̀” (Ilé Ìṣọ́, August 2018)

“Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Dí Ní ‘Apá Ìgbẹ̀yìn Àwọn Ọjọ́’ Yìí” (Ilé Ìṣọ́, October 2019, ìpínrọ̀ 16-18)

Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Wọ́n Tàn Yín Jẹ (9:32)

“Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, July 1, 2011)

59 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Táwọn Èèyàn Bá Tiẹ̀ Ń Ta Kò Ẹ́

Jèhófà Ò Fi Wá Sílẹ̀ (5:13)

Wọ́n Jẹ́ Onígboyà Báwọn Èèyàn Tiẹ̀ Ń Ṣenúnibíni Sí Wọn (6:27)

Jèhófà Máa Fún Mi Lókun (3:40)

ṢÈWÁDÌÍ

Jèhófà Ràn Án Lọ́wọ́ Láti Fara Da Inúnibíni (2:34)

Bá A Ṣe Sin Jèhófà Láwọn Àkókò Tí Nǹkan Ò Dẹrùn (7:11)

“Ìsinsìnyí Gan-an Ni Kó O Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Múra Sílẹ̀ fún Inúnibíni” (Ilé Ìṣọ́, July 2019)

“Idà Ni Òtítọ́ Ń Mú Wá, Kì Í Ṣe Àlàáfíà” (Ilé Ìṣọ́, October 2017)

60 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Sún Mọ́ Jèhófà

Jẹ́ Kí Ọ̀nà Tó Ò Ń Gbà Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Dáa Sí I (5:22)

Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ (3:31)

Sún Mọ́ Jèhófà (ìwé)

“Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn” (ìwé)

ṢÈWÁDÌÍ

Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Bíi Ti Ábúráhámù (9:20)

Wàá Láyọ̀ Tó O Bá Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Tó O sì Ń Ṣàṣàrò (5:25)

“Fi Àwọn Ohun Tó Ò Ń Lé Nípa Tẹ̀mí Yin Ẹlẹ́dàá Rẹ Lógo” (Ilé Ìṣọ́, July 15, 2004)

“Máa Tẹ̀ Síwájú Sí Ìdàgbàdénú Torí Pé ‘Ọjọ́ Ńlá Jèhófà Sún Mọ́lé’” (Ilé Ìṣọ́, May 15, 2009)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́