ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • lff apá 2
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 2

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 2
  • Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 1
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 3
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Fídíò àti Ìwé Tá A Tọ́ka Sí
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì
Àwọn Míì
Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
lff apá 2

Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 2

  1. 13 Ẹ̀sìn Èké Kò Ṣojú fún Ọlọ́run

  2. 14 Báwo La Ṣe Lè Mọ Ìjọsìn Tí Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà?

  3. 15 Ta Ni Jésù?

  4. 16 Kí Ni Jésù Ṣe Nígbà Tó Wà Láyé?

  5. 17 Irú Ẹni Wo Ni Jésù?

  6. 18 Bá A Ṣe Lè Mọ Àwọn Kristẹni Tòótọ́

  7. 19 Ṣé Kristẹni Tòótọ́ Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

  8. 20 Bá A Ṣe Ṣètò Ìjọ Kristẹni

  9. 21 Báwo La Ṣe Ń Wàásù Ìhìn Rere?

  10. 22 Bó O Ṣe Lè Máa Wàásù Ìhìn Rere Fáwọn Èèyàn

  11. 23 Ìrìbọmi Ṣe Pàtàkì!

  12. 24 Ohun Tó Yẹ Ká Mọ̀ Nípa Àwọn Áńgẹ́lì

  13. 25 Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Wa?

  14. 26 Kí Nìdí Tí Nǹkan Burúkú Fi Ń Ṣẹlẹ̀ Tá A sì Ń Jìyà?

  15. 27 Báwo Ni Ikú Jésù Ṣe Gbà Wá Là?

  16. 28 Fi Hàn Pé O Mọyì Ohun Tí Jèhófà àti Jésù Ṣe fún Ẹ

  17. 29 Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Sáwọn Tó Ti Kú?

  18. 30 Àwọn Èèyàn Rẹ Tó Ti Kú Ṣì Máa Jíǹde!

  19. 31 Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?

  20. 32 Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!

  21. 33 Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe fún Aráyé

13 Ẹ̀sìn Èké Kò Ṣojú fún Ọlọ́run

Ṣé Gbogbo Ẹ̀sìn Ni Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà?​—Àyọlò (3:22)

Àwọn Oníṣọ́ọ̀ṣì Lọ́wọ́ sí Ogun Àgbáyé Kejì (2:22)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ṣé Ọ̀kan Náà Ni Gbogbo Ìsìn? Ǹjẹ́ Gbogbo Rẹ̀ Ni Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ṣé Ó Pọn Dandan Kéèyàn Máa Dara Pọ̀ Mọ́ Ẹ̀sìn Kan Pàtó?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ohun Tó Mú Kí Àlùfáà Kan Fi Ṣọ́ọ̀ṣì Rẹ̀ Sílẹ̀” (Jí!, February 2015)

“Àwọn Irọ́ Tí Kò Jẹ́ Káwọn Èèyàn Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run” (Ilé Ìṣọ́, November 1, 2013)

14 Báwo La Ṣe Lè Mọ Ìjọsìn Tí Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà?

Ṣé Ọlọ́run Fẹ́ Ká Máa Lo Ère Nínú Ìjọsìn Wa? (3:26)

Òtítọ́ Sọ Ọ́ Dòmìnira (5:16)

ṢÈWÁDÌÍ

“Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, July 1, 2011)

“Máa Yin Jèhófà Nínú Ìjọ” (Ilé Ìṣọ́, January 2019)

Jèhófà Bìkítà Nípa Mi (3:07)

“Kí Nìdí Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Lo Àgbélébùú Nínú Ìjọsìn Wọn?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

15 Ta Ni Jésù?

Ṣé Jésù Kristi Ni Ọlọ́run? (3:22)

Àsọtẹ́lẹ̀ Ṣẹ sí Jésù Lára (3:03)

‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’​—Apá I (35:24)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ṣé Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Fẹ̀rí Hàn Pé Jésù Ni Mèsáyà Náà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Kí Nìdí Tí A Fi Pe Jésù Ní Ọmọ Ọlọ́run?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run?” (Ilé Ìṣọ́, April 1, 2009)

“Obìnrin Júù Kan Sọ Ìdí Tó Fi Yí Ẹ̀sìn Rẹ̀ Pa Dà” (Jí!, May 2013)

16 Kí Ni Jésù Ṣe Nígbà Tó Wà Láyé?

Jésù Mú Obìnrin Aláìsàn Kan Lára Dá (5:10)

‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’​—Apá II (35:06)

ṢÈWÁDÌÍ

Ẹ̀rù ń ba obìnrin kan lẹ́yìn tó rí ìwòsàn lọ́nà ìyanu, Jésù wá kúnlẹ̀ ó sì ń bá obìnrin náà sọ̀rọ̀.

“Ìjọba Ọlọ́run​—Kí Nìdí Tó fi Ṣe Pàtàkì Gan-an sí Jésù?” (Ilé Ìṣọ́, October 1, 2014)

“Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Jésù​—Kí Lo Lè Rí Kọ́ Látinú Wọn?” (Ilé Ìṣọ́, July 15, 2004)

“Tara Mi Nìkan Ni Mo Mọ̀” (Ilé Ìṣọ́, October 1, 2014)

“Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù” (Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, Àfikún A7)

17 Irú Ẹni Wo Ni Jésù?

“Ayọ̀ Púpọ̀ Wà Nínú Fífúnni”​—Àyọlò (4:00)

ṢÈWÁDÌÍ

“Tó O Bá Fẹ́ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù, Ó Yẹ Kó O . . . ” (Jésù​—Ọ̀nà, Òtítọ́ àti Ìyè, ojú ìwé 317)

“Kí Nìdí Tí Mo Fi Gbọ́dọ̀ Gbàdúrà Lórúkọ Jésù?” (Ilé Ìṣọ́, February 1, 2008)

“Báwo Ni Jésù Ṣe Rí?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Wọ́n Wà Ní Ipò Ọ̀wọ̀ àti Iyì Lójú Ọlọ́run” (Ilé Ìṣọ́, September 1, 2012)

18 Bá A Ṣe Lè Mọ Àwọn Kristẹni Tòótọ́

Wọ́n Sọ Ẹ̀sìn Kristẹni Dìdàkudà (5:11)

Ọ̀rọ̀ Ẹ̀sìn Yọ Lọ́kàn Mi (5:20)

Ó Ṣe Tán Láti Kú Nítorí Ọ̀rẹ́ Rẹ̀ (2:55)

ṢÈWÁDÌÍ

Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà? (1:13)

“Bíbélì Ni Wọ́n Fi Dáhùn Gbogbo Ìbéèrè Mi!” (Ilé Ìṣọ́, April 1, 2014)

Bá A Ṣe Ń Ran Àwọn Ará Wa Lọ́wọ́ Nígbà Àjálù​—Àyọlò (3:57)

“Kí La Lè Fi Dá Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Mọ̀?” (Ilé Ìṣọ́, March 1, 2012)

19 Ṣé Kristẹni Tòótọ́ Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Wọ́n Ṣàwárí Òtítọ́ Látinú Bíbélì (7:45)

Orúkọ Tó Yẹ Wá (2:40)

Ìjì Ńlá Kan Jà Lórílẹ̀-Èdè Haiti (5:29)

ṢÈWÁDÌÍ

Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Ń Gbé Orúkọ Rẹ̀ Ga (7:08)

“Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ìwà Burúkú Ọwọ́ Mi Ń Peléke Sí I” (Ilé Ìṣọ́, July 1, 2015)

20 Bá A Ṣe Ṣètò Ìjọ Kristẹni

Àwọn Alàgbà Dìde Ìrànwọ́ Nígbà Ìmìtìtì Ilẹ̀ Ní Nepal (4:56)

Ẹ̀yin Alàgbà, Ẹ Máa Múpò Iwájú! (7:39)

ṢÈWÁDÌÍ

A Fún Àwọn Ará Wa Lókun Nígbà Tí Wọ́n Fòfin De Iṣẹ́ Wa (4:22)

Ìgbésí Ayé Alábòójútó Àyíká Tó Lọ Sìn ní Ìgbèríko Kan (4:51)

“Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Àwọn Obìnrin Tó Jẹ́ Òjíṣẹ́ Ọlọ́run?” (Ilé Ìṣọ́, September 1, 2012)

“Àwọn Alàgbà Jẹ́ ‘Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Fún Ìdùnnú Wa’” (Ilé Ìṣọ́, January 15, 2013)

21 Báwo La Ṣe Ń Wàásù Ìhìn Rere?

Wíwàásù ní “Apá Ibi Jíjìnnà Jù Lọ ní Ilẹ̀ Ayé” (7:33)

A Ń Gbèjà Ìhìn Rere Lọ́nà Tó Bófin Mu (2:28)

ṢÈWÁDÌÍ

A Wàásù Lákànṣe Láwọn Ibi Térò Pọ̀ Sí Nílùú Paris (5:11)

Àwọn Olùwá-Ibi-Ìsádi Tí Òùngbẹ Tẹ̀mí Ń Gbẹ (5:59)

Mo Láyọ̀ Pé Mo Yan Ohun Tí Ó Tọ́ (6:29)

“Àwọn Akéde Ìjọba Ọlọ́run Gbé Ọ̀rọ̀ Lọ Sílé Ẹjọ́” (Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 13)

22 Bó O Ṣe Lè Máa Wàásù Ìhìn Rere Fáwọn Èèyàn

Mo Gbàdúrà Pé Kí Jèhófà Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà (4:05)

ṢÈWÁDÌÍ

Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò Láti Fúnni Ní Káàdì Ìkànnì JW.ORG (1:43)

“Ṣé O Múra Tán Láti Di Apẹja Èèyàn?” (Ilé Ìṣọ́, September 2020)

Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà (11:59)

“Bá A Ṣe Lè Mú Kí Àwọn Ìbátan Wa Tí Kì í Ṣe Ẹlẹ́rìí Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́” (Ilé Ìṣọ́, March 15, 2014)

23 Ìrìbọmi Ṣe Pàtàkì!

Bá A Ṣe Lè Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Jèhófà (1:11)

ṢÈWÁDÌÍ

“Kí Ni Ìrìbọmi?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Tó O Bá Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tó O sì Mọyì Rẹ̀, Wàá Ṣèrìbọmi” (Ilé Ìṣọ́, March 2020)

“Wọ́n Fẹ́ Kí Èmi Fúnra Mi Wádìí Láti Mọ Ohun Tí Bíbélì Sọ” (Ilé Ìṣọ́, February 1, 2013)

“Ṣó Yẹ Kí N Ṣèrìbọmi?” (Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè​—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì, orí 37)

24 Ohun Tó Yẹ Ká Mọ̀ Nípa Àwọn Áńgẹ́lì

“Ẹ Dojú Ìjà Kọ Èṣù” (5:02)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ta Ni Máíkẹ́lì, Olú-Áńgẹ́lì?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ǹjẹ́ Èṣù Wà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ó Rí Ète Kan Ninu Igbesi-Aye” (Ilé Ìṣọ́, July 1, 1993)

“Àṣírí Iṣẹ́ Òkùnkùn” (Ọ̀nà Tó Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun, apá 5)

25 Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Wa?

Kí Ni Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Ayé?​—Àyọlò (1:41)

Mo Ti Wá Mọ Ìdí Tá A Fi Wà Láyé (5:03)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ọgbà Édẹ́nì, Ṣé Ó Wà Lóòótọ́ Àbí Àròsọ Ni?” (Ilé Ìṣọ́, January 1, 2011)

“Ṣé Ilẹ̀ Ayé Máa Pa Run?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Wa?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

Ní Báyìí, Ohun Tó Dára Ni Mò Ń Fi Ayé Mi Ṣe (3:55)

26 Kí Nìdí Tí Nǹkan Burúkú Fi Ń Ṣẹlẹ̀ Tá A sì Ń Jìyà?

Ta Ló Ń Darí Ayé? (1:24)

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Gbà Pé Ká Máa Jìyà?​—Àyọlò (3:07)

ṢÈWÁDÌÍ

“Kí Ni Ẹ̀ṣẹ̀?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?” (Ilé Ìṣọ́, January 1, 2014)

“Kí Nìdí Tí Ìpakúpa Rẹpẹtẹ Fi Ṣẹlẹ̀? Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Kò Ṣe Fòpin Sí I?”(Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

Àwọn Èèyàn Rere Ló Yí Mi Ká (5:09)

27 Báwo Ni Ikú Jésù Ṣe Gbà Wá Là?

Kí Nìdí Tí Jésù Fi Kú?​—Apá 1 (2:01)

Kí Nìdí Tí Jésù Fi Kú?​—Apá 2 (2:00)

ṢÈWÁDÌÍ

“Báwo Ni Ẹbọ Tí Jésù Fi Ẹ̀mí Rẹ̀ Rú Ṣe Jẹ́ ‘Ìràpadà fún Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ènìyàn’?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Báwo Ni Jésù Ṣe Ń Gbani Là?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Ohun Tí Bíbélì Sọ” (Ilé Ìṣọ́, May 1, 2013)

“Mi Ò Kì Í Ṣe Ẹrú Ìwà Ipá Mọ́” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

28 Fi Hàn Pé O Mọyì Ohun Tí Jèhófà àti Jésù Ṣe fún Ẹ

Ìrántí Ikú Jésù (1:41)

ṢÈWÁDÌÍ

Ó Lo Ara Rẹ̀ Láti Bọlá fún Jèhófà (9:28)

“Máa Lo Ìgbàgbọ́ Nínú Àwọn Ìlérí Jèhófà” (Ilé Ìṣọ́, October 2016)

“Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, August 1, 2011)

“Kí Nìdí Tí Ọ̀nà Tí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Ń Ṣe Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa Fi Yàtọ̀ Sí Ti Àwọn Ẹlẹ́sìn Tó Kù?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

29 Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Sáwọn Tó Ti Kú?

Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Tó Ti Kú?​—Àyọlò (1:19)

ṢÈWÁDÌÍ

“Kí Ni Ọkàn?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

Ṣé Òótọ́ Ni Pé Àwọn Ẹni Burúkú Máa Joró Nínú Ọ̀run Àpáàdì? (3:07)

Ẹmi Awọn Oku​—Wọn Ha Le Ran Ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha Wa Niti Gidi Bi? (ìwé pẹlẹbẹ)

“Àwọn Ìdáhùn Tó Bọ́gbọ́n Mu Tí Mo Rí Nínú Bíbélì Wú Mi Lórí Gan-an” (Ilé Ìṣọ́, February 1, 2015)

30 Àwọn Èèyàn Rẹ Tó Ti Kú Ṣì Máa Jíǹde!

Jésù Jí Lásárù Dìde (1:16)

Báwo Ni Ìrètí Àjíǹde Ṣe Ń Jẹ́ Ká Ní Ìgboyà? (3:21)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀” (Jí! No. 3 2018)

Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú (5:06)

Ìràpadà (2:07)

“Kí Ni Àjíǹde?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

31 Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?​—Àyọlò (1:41)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ṣé Inú Ọkàn Rẹ Ni Ìjọba Ọlọ́run Wà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

Ìjọba Ọlọ́run Ni Wọ́n Fara Mọ́ (1:43)

“Àwọn Wo Ló Ń Lọ sí Ọ̀run?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Mo Ti Wá Mọ Bí Àìṣẹ̀tọ́ Ṣe Máa Dópin” (Jí!, July-September 2011)

32 Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!

Ọdún 1914 Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso (5:02)

Ọdún 1914 Ni Ayé Yí Pa Dà Bìrí (1:10)

ṢÈWÁDÌÍ

“Bí Ìwà Rere Ṣe Ṣàdédé Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Jó Rẹ̀yìn” (Jí!, April 2007)

“Mo Fẹ́ràn Baseball Gan-an!” (Ilé Ìṣọ́ No. 3 2017)

“Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀? (Apá 1)” (Ilé Ìṣọ́, October 1, 2014)

“Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀? (Apá 2)” (Ilé Ìṣọ́, November 1, 2014)

33 Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe fún Aráyé

Jésù Jẹ́ Ká Mọ Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe (1:13)

Àwọn Ohun Àgbàyanu Tó Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la (4:38)

Kí ni Ìjọba Ọlọ́run? (ìwé)

ṢÈWÁDÌÍ

“Kí Ni Ogun Amágẹ́dọ́nì?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

“Kí Ni Ìpọ́njú Ńlá?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)

Wo Ara Rẹ Bíi Pé O Wà ní Párádísè (1:50)

“Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, January 1, 2012)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́