Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 1 Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Púpọ̀ Látinú Ẹ̀kọ́ Bíbélì Yìí 01 Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́? 02 Bíbélì Sọ Pé Ọ̀la Ń Bọ̀ Wá Dáa 03 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Gbára Lé Bíbélì? 04 Ta Ni Ọlọ́run? 05 Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá 06 Ṣé Ayé àti Ọ̀run Ní Ìbẹ̀rẹ̀? 07 Irú Ẹni Wo Ni Jèhófà? 08 Bó O Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà 09 Máa Gbàdúrà Kó O Lè Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run 10 Àǹfààní Tó O Máa Rí Ní Ìpàdé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà 11 Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Púpọ̀ Látinú Bíbélì 12 Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Nìṣó Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Púpọ̀ Látinú Ẹ̀kọ́ Bíbélì Yìí Ohun Tó O Máa Gbádùn Nínú Ẹ̀kọ́ Bíbélì Rẹ (2:45) 01 Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́? Má Ṣe Sọ̀rètí Nù! (1:48) Kíka Bíbélì (2:05) ṢÈWÁDÌÍ “Ìlànà Bíbélì Wúlò Títí Láé” (Ilé Ìṣọ́ No. 1 2018) Mo Bẹ̀rẹ̀ Ìgbé Ayé Ọ̀tun (2:53) “Ohun Méjìlá Tó Ń Mú Kí Ìdílé Láyọ̀” (Jí! No. 2 2018) Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn (3:14) 02 Bíbélì Sọ Pé Ọ̀la Ń Bọ̀ Wá Dáa Mo Fẹ́ Jà fún Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn (4:07) ṢÈWÁDÌÍ “Ǹjẹ́ Ó Ní Nǹkan Tí Ìrètí Lè Ṣe fún Wa?” (Jí!, May 8, 2004) “Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ń Ṣàìsàn Ọlọ́jọ́ Pípẹ́?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) Fojú Inú Wò Ó (3:37) “Kò Ṣe Mí Mọ́ Bíi Pé Mo Gbọ́dọ̀ Yí Ayé Yìí Pa Dà” (Ilé Ìṣọ́, July 1, 2013) 03 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Gbára Lé Bíbélì? Ayé Rọ̀ Sórí Òfo (1:13) Bíbélì Sọ Asọtẹ́lẹ̀ Nípa Bí Wọ́n Ṣe Máa Ṣẹ́gun Bábílónì (0:58) ṢÈWÁDÌÍ “Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Bá Ohun Tí Bíbélì Sọ Mu?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Mẹ́fà Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Tó Ń Ṣẹ Lójú Wa” (Ilé Ìṣọ́, May 1, 2011) “Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀” Ń Fúnni Lókun (5:22) “Ní Tèmi O, Kò Sí Ọlọ́run” (Ilé Ìṣọ́ No. 5 2017) 04 Ta Ni Ọlọ́run? Àfikún A4 (Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun) Ó Ní Orúkọ Oyè Tó Pọ̀, Àmọ́ Orúkọ Kan Ṣoṣo Ló Ní (0:41) Ṣé Ọlọ́run Ní Orúkọ?—Àyọlò (3:11) Mo Sapá Láti Wá Ọlọ́run Tòótọ́ (8:18) ṢÈWÁDÌÍ “Ǹjẹ́ Ọlọ́run Wà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Ta Ló Dá Ọlọ́run?” (Ilé Ìṣọ́, August 1, 2014) “Ta Ni Jèhófà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Orúkọ Mélòó Ni Ọlọ́run Ní?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) 05 Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá Ta Ni Òǹṣèwé Bíbélì?—Àyọlò (2:48) Wọ́n Mọyì Bíbélì—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale (6:17) ṢÈWÁDÌÍ “Bí Bíbélì Ṣe Tẹ̀ Wá Lọ́wọ́” (Jí!, November 2007) “Bí Ọlọ́run Ṣe Pa Bíbélì Mọ́” (Ilé Ìṣọ́ No. 4 2016) Wọ́n Mọyì Bíbélì (14:26) “Ṣé Wọ́n Ti Yí Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì Pa Dà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) 06 Ṣé Ayé àti Ọ̀run Ní Ìbẹ̀rẹ̀? Ọlọ́run Wà Lóòótọ́ (2:43) Ṣé Ọlọ́run Ló Dá Àgbáálá Ayé Yìí? (3:51) ṢÈWÁDÌÍ “Kí Ni Àwọn Ohun Alààyè Kọ́ Wa?” (Jí!, September 2006) “Jèhófà . . . Ni Ó Dá Ohun Gbogbo” (2:37) “Ṣé Ẹfolúṣọ̀n Ni Ọlọ́run Lò Láti Dá Àwọn Nǹkan?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) 07 Irú Ẹni Wo Ni Jèhófà? Jèhófà Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Lọ́wọ́ Ìyà (2:45) Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Wa—Ara Èèyàn (1:57) ṢÈWÁDÌÍ “Irú Ẹni Wo Ni Ọlọ́run?” (Ilé Ìṣọ́ No. 1 2019) “Ṣé Ibi Gbogbo Ni Ọlọ́run Wà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Kí Ni Ẹ̀mí Mímọ́?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Mo Ti Lè Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Báyìí” (Ilé Ìṣọ́, October 1, 2015) 08 Bó O Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà Ọ̀pọ̀ Nǹkan Ni Jèhófà Ti Ṣe fún Mi (3:20) ṢÈWÁDÌÍ “Jèhófà—Ọlọ́run Tó Yẹ Ká Mọ̀ Dáadáa” (Ilé Ìṣọ́, February 15, 2003) “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?” (Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì, orí 35) “Mi Ò Fẹ́ Kú O!” (Ilé Ìṣọ́ No. 1 2017) Àǹfààní Wo Ló Máa Ṣe Ẹ́ Tó O Bá Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run? (1:46) 09 Máa Gbàdúrà Kó O Lè Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run Ṣé Gbogbo Àdúrà Ni Ọlọ́run Máa Ń Gbọ́?—Àyọlò (2:42) Àdúrà Ló Ràn Wá Lọ́wọ́ (1:32) ṢÈWÁDÌÍ “Ohun Méje Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Àdúrà” (Ilé Ìṣọ́, October 1, 2010) “Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Gbàdúrà?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Ṣó Yẹ Kí N Máa Gbàdúrà sí Àwọn Ẹni Mímọ́?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) Gbàdúrà Nígbà Gbogbo (1:22) 10 Àǹfààní Tó O Máa Rí Ní Ìpàdé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? (2:12) ṢÈWÁDÌÍ A Ò Lè Gbàgbé Ìkíni Yẹn Láyé (4:16) Mo Gbádùn Ìpàdé Yẹn Gan-an! (4:33) “Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Lọ sí Gbọ̀ngàn Ìjọba?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Ìbọn Máa Ń Wà Lára Mi Níbikíbi Tí Mo Bá Lọ” (Ilé Ìṣọ́, July 1, 2014) 11 Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Púpọ̀ Látinú Bíbélì Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Kọ́ Bí Wọ́n Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (5:33) “Ṣé Bíbélì Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Yàtọ̀?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) ṢÈWÁDÌÍ “Bó O Ṣe Lè Rí Ẹ̀kọ́ Kọ́ Látinú Kíka Bíbélì” (Ilé Ìṣọ́ No. 1 2017) “Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá Kìíní: Wo Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) “Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá Kejì: Jẹ́ Kí Bíbélì Gbádùn Mọ́ Ẹ” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì) Ẹ Máa Ṣe Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Tó Jíire (2:06) 12 Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Nìṣó Ìfaradà Rẹ̀ Lérè (5:22) Jèhófà Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Ṣe Àyípadà Tó Yẹ (3:56) ṢÈWÁDÌÍ “Bó O Ṣe Lè Máa Lo Àkókò Rẹ Lọ́nà Tó Dáa” (Jí!, February 2014) Jèhófà Ń Fún Wa Lókun Ká Lè Gbé Ẹrù Wa (5:05) Mo Wádìí Òtítọ́ Wò (6:30) “Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Tú Ìdílé Ká Ni àbí Wọ́n Ń Mú Kí Ìdílé Wà Níṣọ̀kan?” (Àpilẹ̀kọ orí ìkànnì)