ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • lfb ojú ìwé 38-39
  • Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 4

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 4
  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 11
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Ó Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Ní Ìfaradà
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • ‘Onídàájọ́ Ilẹ̀ Ayé’ Máa Ń Ṣe Ohun Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Ó Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Lo Ìfaradà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Àwọn Míì
Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
lfb ojú ìwé 38-39
Mósè àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń wo bí Òkun Pupa ṣe pínyà

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 4

Apá yìí máa jẹ́ ká mọ̀ nípa Jósẹ́fù, Jóòbù, Mósè àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Gbogbo wọn fara da àwọn ìṣòro tí Èṣù gbé kò wọ́n. Wọ́n fìyà jẹ àwọn kan, wọ́n sì sọ àwọn míì sẹ́wọ̀n. Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n sọ àwọn kan di ẹrú, àwọn míì sì pàdánù àwọn èèyàn wọn. Síbẹ̀, Jèhófà dáàbò bò wọ́n ní onírúurú ọ̀nà. Tó o bá jẹ́ òbí, ran ọmọ ẹ lọ́wọ́ kó lè rí báwọn ìránṣẹ́ Jèhófà yẹn ṣe jẹ́ olóòótọ́ láìka ìyà tí wọ́n jẹ.

Jèhófà lo ìyọnu mẹ́wàá (10) láti fi hàn pé òun lágbára ju àwọn òrìṣà táwọn ọmọ Íjíbítì ń bọ. Jẹ́ káwọn ọmọ ẹ rí bí Jèhófà ṣe dáàbò bo àwọn ìránṣẹ́ ẹ̀ láyé àtijọ́ àti bó ṣe ń dáàbò bò wọ́n lónìí.

Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ

  • Jósẹ́fù kọ̀ láti ṣèṣekúṣe torí pé ó nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

  • Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Jóòbù jìyà gan-an, kò fi Jèhófà sílẹ̀

  • Ibi yòówù kí Mósè wà, kò gbàgbé pé ìránṣẹ́ Jèhófà lòun

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́