ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 13
  • Kristi, Àwòkọ́ṣe Wa

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kristi, Àwòkọ́ṣe Wa
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Ọlọ́run?
    Jí!—2012
  • Máa Gbé Ìgbé Ayé Rẹ Ní Ìbámu Pẹ̀lú Àdúrà Àwòṣe Náà Apá Kìíní
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
  • Jèhófà Ń pèsè Àwọn Ohun Tá a Nílò Lójoojúmọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • “Tọ Ipasẹ̀ Rẹ̀ Pẹ́kípẹ́kí”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 13

ORIN 13

Kristi, Àwòkọ́ṣe Wa

Bíi Ti Orí Ìwé

(1 Pétérù 2:21)

  1. 1. Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa,

    Ó ṣoore ńlá fún wa.

    Ó fọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n r’aráyé pa dà.

    Nígbà tó wá sáyé,

    Àpẹẹrẹ rere ni.

    Ìwà rẹ̀ gbórúkọ Ọlọ́run ga.

  2. 2. Ọ̀rọ̀ Jèhófà yè;

    Ó fún Jésù nímọ̀,

    Ó sì fún un lóye, ó gbé ẹ̀mí rẹ̀ ró.

    Bó ṣe j’ónírẹ̀lẹ̀

    Jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa.

    Ó máa ń wù ú láti ṣèfẹ́ Jèhófà.

  3. 3. Bíi ti Jésù Kristi,

    Kígbèésí ayé wa

    Máa mú ìyìn bá Jèhófà Bàbá wa.

    Ká fìwà jọ Jésù

    Lójoojúmọ́ ayé,

    Ká lè máa rójú rere Jèhófà.

(Tún wo Jòh. 8:29; Éfé. 5:2; Fílí. 2:​5-7.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́