ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 8A
Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà—Igi Kédárì Ńlá
Bíi Ti Orí Ìwé
ÌSÍKÍẸ́LÌ 17:3-24
1. Nebukadinésárì mú Jèhóákínì lọ sí Bábílónì
2. Nebukadinésárì fi Sedekáyà sórí ìtẹ́ ní Jerúsálẹ́mù
3. Sedekáyà ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà, ó wá ìrànlọ́wọ́ lọ sí Íjíbítì nígbà tó fẹ́ jagun
4. Jèhófà gbin Ọmọ rẹ̀ sórí Òkè Síónì ní ọ̀run
5. Lábẹ́ òjìji Ìjọba Jésù, àwọn èèyàn tí wọ́n jẹ́ onígbọràn máa gbé lábẹ́ ààbò