ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rr ojú ìwé 106
  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìgbèkùn àti Ìmúbọ̀sípò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìgbèkùn àti Ìmúbọ̀sípò
  • Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • “Èmi Yóò Mú Kí Ọkàn Wọn Ṣọ̀kan”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Àtẹ Àwọn Ọjọ́ Ìṣẹ̀lẹ̀
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
Àwọn Míì
Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
rr ojú ìwé 106

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 9E

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìgbèkùn àti Ìmúbọ̀sípò

Bíi Ti Orí Ìwé

Ọ̀pọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tó ṣẹ sára àwọn Júù tí wọ́n kó nígbèkùn lọ sí Bábílónì àtijọ́ tún ṣẹ lọ́nà tó gbòòrò nígbà tí Bábílónì Ńlá mú ìjọ Kristẹni nígbèkùn. Àwọn àpẹẹrẹ kan rèé.

1. ÌKÌLỌ̀

2. ÌGBÈKÙN

3. ÌMÚBỌ̀SÍPÒ

ÌMÚṢẸ ÀKỌ́KỌ́

Ṣáájú 607 Ṣ.S.K.​—Àìsáyà, Jeremáyà àti Ìsíkíẹ́lì kìlọ̀ fáwọn èèyàn Jèhófà; síbẹ̀ ìpẹ̀yìndà ń gbilẹ̀ sí i

607 Ṣ.S.K.​—Jerúsálẹ́mù pa run; wọ́n kó àwọn èèyàn Ọlọ́run lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì

537 Ṣ.S.K. síwájú​—Àwọn àṣẹ́kù tó jẹ́ olóòótọ́ pa dà sí Jerúsálẹ́mù, wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìjọsìn mímọ́

ÌMÚṢẸ TÓ GBÒÒRÒ

Ọgọ́rùn-ún Ọdún Kìíní S.K.​—Jésù, Pọ́ọ̀lù àti Jòhánù kìlọ̀ fún ìjọ, síbẹ̀ ìpẹ̀yìndà ń gbilẹ̀ sí i

Láti Ọgọ́rùn-ún Ọdún Kejì S.K.​—Bábílónì Ńlá mú àwọn Kristẹni tòótọ́ nígbèkùn

1919 S.K. síwájú​—Lábẹ́ àkóso Jésù, àwọn olóòótọ́ ẹni àmì òróró kúrò nínú ìgbèkùn tẹ̀mí, ìjọsìn mímọ́ sì pa dà bọ̀ sípò

Pa dà sí orí 9, ìpínrọ̀ 6 sí 11 àti 25 sí 32

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́