ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rr ojú ìwé 108
  • ‘Àkókò Ìmúbọ̀sípò Ohun Gbogbo’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Àkókò Ìmúbọ̀sípò Ohun Gbogbo’
  • Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ÌṢE 3:21
  • “Àwọn Àkókò Ìmúpadàbọ̀sípò” Ti Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • “Èmi Yóò Mú Kí Ọkàn Wọn Ṣọ̀kan”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Agbára Ìmúbọ̀sípò—Jèhófà “Ń Sọ Ohun Gbogbo Di Tuntun”
    Sún Mọ́ Jèhófà
  • Ohun Tí Kristi Máa Ṣe Tó Bá Dé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
rr ojú ìwé 108

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 9Ẹ

‘Àkókò Ìmúbọ̀sípò Ohun Gbogbo’

Bíi Ti Orí Ìwé

ÌṢE 3:21

Nígbà tí àpọ́sítélì Pétérù ń sọ̀rọ̀ nípa ‘àkókò ìmúbọ̀sípò ohun gbogbo,’ ṣe ló ń sọ tẹ́lẹ̀ nípa àkókò gígùn kan tó máa bẹ̀rẹ̀ látìgbà tí Kristi bá di Ọba títí dé ìparí Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso Kristi.

  1. 1914​—Jésù Kristi di Ọba ní ọ̀run. Àwọn èèyàn Ọlọ́run bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò nínú ìgbèkùn tẹ̀mí lọ́dún 1919

    Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn

  2. AMÁGẸ́DỌ́NÌ​—Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso Kristi bẹ̀rẹ̀, ‘àkókò ìmúbọ̀sípò ohun gbogbo’ sì tún máa mú kí àwọn olóòótọ́ èèyàn lórí ilẹ̀ ayé gbádùn àwọn ìbùkún tara

    Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso

  3. ẸGBẸ̀RÚN ỌDÚN ÌṢÀKÓSO KRISTI PARÍ​—Jésù parí iṣẹ́ rẹ̀ láti mú kí gbogbo nǹkan pa dà bọ̀ sípò, ó sì dá Ìjọba náà pa dà fún Bàbá rẹ̀

    Párádísè Títí Ayé

Ìdílé kan ń gbádùn ara wọn lórí pèpéle etí omi adágún kan nínú Párádísè orí ilẹ̀ ayé.

ÌṢÀKÓSO JÉSÙ MÁA MÚ KÍ . . .

  • orúkọ Ọlọ́run pa dà di ológo

  • ara àwọn aláìsàn yá

  • àwọn arúgbó pa dà di ọ̀dọ́

  • àwọn òkú jíǹde

  • àwọn olóòótọ́ èèyàn pa dà di ẹni pípé

  • ayé pa dà di Párádísè

Pa dà sí orí 9, ìpínrọ̀ 23 àti 33 sí 39

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́