ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rr ojú ìwé 131
  • Síso Igi Méjì Pọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Síso Igi Méjì Pọ̀
  • Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “ti Júdà”
  • “ti Jósẹ́fù, igi Éfúrémù”
  • ‘wọ́n di igi kan ṣoṣo ní ọwọ́ rẹ’
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • “Èmi Yóò Sọ Wọ́n Di Orílẹ̀-Èdè Kan”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Gbígbẹ́ Ọnà Ọ̀pá Ìtẹ̀lẹ̀
    Jí!—1998
  • Igi Tẹ́ẹ́rẹ́ Tó Ń Fọ Eyín Mọ́
    Jí!—2003
Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
rr ojú ìwé 131

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 12A

Síso Igi Méjì Pọ̀

Bíi Ti Orí Ìwé

Jèhófà sọ fún Ìsíkíẹ́lì pé kó kọ “ti Júdà” sára ọ̀kan, kó sì kọ “ti Jósẹ́fù, igi Éfúrémù” sára ìkejì.

Igi méjì inú asọtẹ́lẹ̀ Ìsíkíẹ́lì.

“ti Júdà”

NÍGBÀ ÀTIJỌ́

Ìjọba ẹ̀yà méjì ti Júdà

LÓDE ÒNÍ

Àwọn ẹni àmì òróró

“ti Jósẹ́fù, igi Éfúrémù”

NÍGBÀ ÀTIJỌ́

Ìjọba ẹ̀yà mẹ́wàá ti Ísírẹ́lì

LÓDE ÒNÍ

Àwọn àgùntàn mìíràn

Ìsíkíẹ́lì fi ọwọ́ kan mú igi méjì dání.

‘wọ́n di igi kan ṣoṣo ní ọwọ́ rẹ’

NÍGBÀ ÀTIJỌ́

537 Ṣ.S.K. Àwọn olùjọsìn tòótọ́ pa dà dé láti ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè, wọ́n tún Jerúsálẹ́mù kọ́, wọ́n sì ń jọ́sìn pa pọ̀ bí orílẹ̀-èdè kan.

LÓDE ÒNÍ

Látọdún 1919, àwọn èèyàn Ọlọ́run ti wà níṣọ̀kan, wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ pọ̀ bí “agbo kan.”

Ìṣọ̀kan àwọn èèyàn Ọlọ́run ló dá lé

Àsọtẹ́lẹ̀ náà ò sọ nípa igi kan tí wọ́n ṣẹ́ sí méjì, tí wọ́n wá pa dà so pọ̀. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sọ nípa igi méjì tí wọ́n so pọ̀ di ọ̀kan ṣoṣo. Torí náà, kì í ṣe bí orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì ṣe pín sí méjì ni àsọtẹ́lẹ̀ náà dá lé. Dípò bẹ́ẹ̀, ohun tó dá lé ni bí ìjọba méjì ṣe máa pa dà di ọ̀kan.

Pa dà sí orí 12, ìpínrọ̀ 3 sí 6, 13 àti 14

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́