ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CA-brpgm20 ojú ìwé 4
  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2019-2020—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2019-2020—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2022-2023—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2020-2021—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2019-2020—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
CA-brpgm20 ojú ìwé 4

Wá Ìdáhùn Sí Àwọn Ìbéèrè Yìí:

  1. Báwo la ṣe lè fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run? (Diu. 13:3, 4; 1 Jòh. 5:3)

  2. Kí nìdí tó fi yẹ ká nífẹ̀ẹ́ àwọn ará wa? (1 Jòh. 4:11, 20, 21)

  3. Báwo la ṣe lè fìfẹ́ hàn sí ọmọnìkejì wa? (Léf. 19:18; Éfé. 5:29)

  4. Báwo la ṣe lè máa fìfẹ́ hàn bíi ti Jèhófà? (1 Pét. 4:8; Kól. 3:13)

  5. Kí ló lè ràn wá lọ́wọ́ láti máa yin Jèhófà? (Sm. 104:33; 146:2, 5)

  6. Kí ló túmọ̀ sí láti fi gbogbo ọkàn wa nífẹ̀ẹ́ Jèhófà? (Ẹ́kís. 34:14; Émọ́sì 5:15; Róòmù 12:11)

© 2019 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́