ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CA-brpgm24 ojú ìwé 4
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2020-2021—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2024-2025—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2021-2022—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2019-2020—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
CA-brpgm24 ojú ìwé 4

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:

  1. 1. Báwo la ṣe lè wọnú ìsinmi Ọlọ́run? (Jẹ́n. 2:1-3; Héb. 4:1, 11)

  2. 2. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí agbára tí “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” ní hàn láyé wa? (1 Tẹs. 2:13; Héb. 4:12)

  3. 3. Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kí Jèhófà máa tọ́ wa sọ́nà? (Àìsá. 26:7-9, 15, 20)

  4. 4. Kí ló yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ kí Jèhófà bù kún wa? (1 Pét. 1:13-15; 1 Jòh. 5:3)

  5. 5. Báwo la ṣe lè mú inú Jèhófà dùn? (Sm. 71:14, 15; Róòmù 12:2; 1 Pét. 4:10)

  6. 6. Kí lá jẹ́ ká túbọ̀ máa láyọ̀ bá a ṣe ń sin Jèhófà? (Jòh. 5:17)

© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

CA-brpgm24-YR

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́