ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CA-brpgm22 ojú ìwé 4
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2021-2022—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2021-2022—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2018-2019—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Ìgbàgbọ́—Ànímọ́ Tó Ń Sọni Di Alágbára
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2021-2022—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
CA-brpgm22 ojú ìwé 4

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:

  1. 1. Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kígbàgbọ́ wa lágbára báyìí? (Héb. 10:39)

  2. 2. Báwo la ṣe lè “rí” Jèhófà bó tiẹ̀ jẹ́ pé a ò lè rí i lójúkojú? (Héb. 11:27)

  3. 3. Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì ká máa ṣàyẹ̀wò àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì? (Róòmù 10:17)

  4. 4. Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ ṣe lè jẹ́ ká nígbàgbọ́? (Lúùkù 11:13; Gál. 5:22)

  5. 5. Báwo la ṣe lè ran àwọn míì lọ́wọ́ kí ìgbàgbọ́ wọn lè lágbára? (1 Tẹs. 2:7, 8)

  6. 6. Kí nìdí tó fi yẹ ká máa “tẹjú mọ́ . . . Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa”? (Héb. 12:2, 3)

© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

CA-brpgm22-YR

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́