Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Ẹ Túbọ̀ Lágbára!
ÒWÚRỌ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 119 àti Àdúrà
10:00 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kígbàgbọ́ Wa Lágbára Báyìí?
10:15 Ṣé Ò Ń Rí “Ẹni Tí A Kò Lè Rí”?
10:30 “Ìgbàgbọ́ Ń Tẹ̀ Lé Ohun Tí A Gbọ́”
10:55 Orin 104 àti Ìfilọ̀
11:05 “Èso ti Ẹ̀mí Ni . . .Ìgbàgbọ́”
11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:05 Orin 50