Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run!
Àárọ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 87 àti Àdúrà
10:00 Báwo La Ṣe Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run?
10:15 Ṣé Lóòótọ́ ni “Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Wà Láàyè”?
10:30 Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Tọ́ Ẹ Sọ́nà
10:55 Orin 89 àti Ìfilọ̀
11:05 Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Bá Ń Ṣègbọràn
11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:05 Orin 32