Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Pẹ̀lú Gbogbo Ọkàn Rẹ
ÒWÚRỌ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 109 àti Àdúrà
10:00 “Ohun Tí Ìfẹ́ Ọlọ́run Túmọ̀ Sí Nìyí”
10:15 Jèhófà Là Ń Fìfẹ́ Hàn Sí Tá A Bá Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ará Wa
10:30 “Nífẹ̀ẹ́ Ọmọnìkejì Rẹ Bí Ara Rẹ”
10:55 Orin 82 àti Ìfilọ̀
11:05 “Ìfẹ́ Máa Ń Bo Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ẹ̀ṣẹ̀ Mọ́lẹ̀”
11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:05 Orin 50