Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!
ÒWÚRỌ̀
9:30 Ohùn Orin
9:40 Orin 29 àti Àdúrà
9:50 Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!
10:05 Àpínsọ Àsọyé: Fìwà Jọ Jèhófà Láwọn Ọ̀nà Pàtàkì Yìí
• Ó Jẹ́ Onídàájọ́ Òdodo
• Ó Jẹ́ Alágbára
• Ó Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
• Ó Jẹ́ Onífẹ̀ẹ́
11:05 Orin 81 àti Ìfilọ̀
11:15 Máa “So Èso Púpọ̀” Kó O Lè Fògo fún Ọlọ́run
11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 Orin 49
Ọ̀SÁN
1:10 Ohùn Orin
1:20 Orin 28 àti Àdúrà
1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Bí O Ṣe Lè Mú Ọkàn Ọlọ́run Yọ̀
2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 Orin 35 àti Ìfilọ̀
2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa Ṣe Ohun Tí Inú Jèhófà Dùn Sí . . .
• Ní Ìgbésí Ayé Rẹ
• Nínú Ìdílé Rẹ
• Nínú Ìjọ Rẹ
• Ní Àdúgbò Rẹ
3:40 “Ìdùnnú Jèhófà Ni Agbára Yín”
4:15 Orin 110 àti Àdúrà