ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 February ojú ìwé 2
  • Nehemáyà Fẹ́ràn Ìjọsìn Tòótọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Nehemáyà Fẹ́ràn Ìjọsìn Tòótọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Nehemáyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • “Máa Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Alábòójútó Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ Ni Nehemáyà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • “Jọ̀wọ́, Ọlọ́run Mi, Rántí Mi fún Rere”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 February ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | NEHEMÁYÀ 1-4

Nehemáyà Fẹ́ràn Ìjọsìn Tòótọ́

Bíi Ti Orí Ìwé

455 B.C.E.

  1. Nísàn (Mar. sí Apr.)

    2:4-6 Nehemáyà gba àṣẹ láti tún Jerúsálẹ́mù tí wọ́n ti ń ṣe ìjọsìn tòótọ́ ní àkókò rẹ̀ kọ́

  2. Ííyà

  3. Sífánì

  4. Támúsì (June sí July)

    2:11-15 Nehemáyà dé Jerúsálẹ́mù nírú àkókò yìí, ó sì ṣàyẹ̀wò ògiri ìlú náà

  5. Ábì (July sí Aug.)

    3:1; 4:7-9 Wọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìkọ́lé náà láìka àtakò sí

  6. Élúlì (Aug. sí Sept.)

    6:15 Wọ́n parí mímọ ògiri náà lẹ́yìn ọjọ́ méjìléláàádọ́ta [52]

  7. Tíṣírì

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́